Jump to content

Titilope Gbemisola Akosa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Titilope Gbemisola Akosa
Ọjọ́ìbíTitilope Gbemisola Ngozi Akosa
Lagos, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Ọmọ orílẹ̀-èdèNigeria
Iṣẹ́Lawyer, Activist
Ìgbà iṣẹ́2004–present
Gbajúmọ̀ fúnActivism
Notable workCentre for 21st Century Issues (C21st)

Titilope Gbemisola Akosa tí gbogbo ènìyàn mọ́ sì Titolope Akosa jẹ agbejọ́rọ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà[1]. Òun ni olùdásílẹ̀ ilé iṣẹ́ Titi Akosa & Co ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ní ọdún 2015, ó jẹ́ agbenuso fún àwọn obìnrin lórí ètò tí àkọlé rẹ jẹ́ Towards a Gender Responsive Green Climate Fund in Africa ní ibí ayẹyẹ Paris Climate Treaty.[2][3][4][5][6]

Ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ayé àti ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí Títí sì ìlú Èkó, ibè sì ni ó dàgbà sì. Ó gboyè nínú ìmò òfin láti ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Lagos State University, ó sì tẹ̀ síwájú sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí University of Lagos níbi tí ó tí gbà masters rẹ̀.

Akosa dá ilé iṣẹ́ tirẹ̀ tí ó pè ní Títí Akosa & Co pẹ̀lú àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ mìíràn, òun sì ni olórí àti olùkọ́ni onímòràn nípa òfin fún ilé iṣẹ́ náà[7].

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]