Tobechi Nneji
Tobe Da Diva | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Tobechi Lawrencia Nneji 19 Oṣù Kínní 1987 Lagos |
Ẹ̀kọ́ | |
Iṣẹ́ | On-Air Personality, TV host, Vlogger |
Ìgbà iṣẹ́ | 2007–2016 |
Website | http://www.tobedadiva.com |
Tobechi Lawrence Nneji (bíi ni ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kìíní ọdún 1987) tí orúkọ inagi rẹ jẹ Tobe Da Diva jẹ́ agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati atọkun ètò lórí telefisionu. Ní ọdún 2013, ThisDay ni pé ètò rẹ ni àwọn gbọ́ ju ni ọ́sán ni apa Ìlà-Oòrùn ni orile-ede Nàìjíríà.[1] Ní ọdún 2013, ó gbajúmọ̀ fún àwọn ètò bíi Top Ten Most àti The Music Commentators tí ó ti ṣe atọkun fún ní Channel O. Ó ṣe asoju fún Nàìjíríà ni BET's Top Actor Africa tí won ṣe ni ìgbà kejì.[2][3][4] Ó ní eto kàn tí ó ń ṣe tí o fi wan àwọn agbóhùnsáfẹ́fẹ́ tó ṣẹ̀ṣẹ̀ bẹ̀rẹ̀.[5]
Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Òun ni àbíkẹ́yìn nínú àwon omo márùn-ún tí àwọn òbí rẹ bí. Ó jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Imo. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Queens College ni ìpínlè Èkó. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga tí Madonna University ni bẹ sì ni ó ti gboyè Economics ní ọdún 2007. Ó tesiwaju sì ilẹ̀ ẹ̀kọ́ University fún Masters degree rẹ ninu Economics.
Iṣẹ́
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ní ọjọ́ karùn-ún lélógún, oṣù Kejìlá ọdún 2007, ní o kọ́kọ́ ṣe agbóhùnsáfẹ́fẹ́ fún Vision Fm ni Abuja.[6] Ó lọ sí Kiss Fm ni ọdún 2009, ó sì di olórí àwọn agbóhùnsáfẹ́fẹ́
ni odun 2011. Óun ni atọkun ètò Ìrírí òwúrò àti Naijalysis.[7] Ní ọdún 2012, ó lọ dára pọ mọ́ Dream Fm ni Enugu, ó sì di adarí ètò níbè. Tobechi tí si ṣé pẹlu awọn ile iṣẹ́ bíi Gulder, Amstel Malta, Nokia àti Airtel gẹ́gẹ́ bí olóòtu fún àwọn ètò wọn. Ní ọdún 2012, ó wá láàárín àwọn ò lù díje ní MTV Base Vj Search.[8][9] Ní ọdún tí ó tè le, ó kó pá nínú ìdíje The next Titan TV Show, ó sì gbé ipò kẹfà.[10] Tobechi je ìkan láàrín àwọn òṣèré nínú BET'S Top Actor Africa, èyí sì ni ìgbà àkọ́kọ́ tí ó má se ere.[11][12][13][14] Ní ọdún 2017, kí ṣe ère ìwé ìtan fún ayẹyẹ ojo ibí, ó sì pe àkọlé rẹ ni The 4th Decade.[15] Ó dà ètò MPW Podcast Series àti The presenters Vlog kalè láti lè pèsè iranlowo fún àwọn tí ó bá fẹ́ ṣe agbóhùnsáfẹ́fẹ́.[16]
Ẹ̀bùn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Award | Category | Result | Notes |
---|---|---|---|---|
2014 | Nigeria Broadcasters' Merit Awards | Outstanding Presenter on a midday show (south east) | Gbàá | |
Nigeria Broadcasters' Merit Awards | Nigerian Broadcaster Of The Year | Wọ́n pèé | ||
Nigeria Broadcasters' Merit Awards | sexiest OAP ( Female) | Wọ́n pèé | ||
Scream Youth Awards | on-air personality of the year | Wọ́n pèé | ||
2013 Nigeria Broadcasters' Merit Awards | Outstanding Presenter on a midday show (south east) | Wọ́n pèé | ||
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ http://www.thisdaylive.com/articles/behind-the-mic-2[Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́] -/142369/
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2017-02-08. Retrieved 2020-05-15.
- ↑ "TheNET.ng - Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games". Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-12-21.
- ↑ "BET Top Actor Africa: Meet Tobechi, Uriel, Dike, The Nigerian Contestants - Vanguard News" (in en-US). Vanguard News. 2016-03-07. http://www.vanguardngr.com/2016/03/bet-top-actor-africa-meet-tobechi-nneji-uriel-oputa-and-ifeanyi-dike-the-nigerian-contestants/.
- ↑ "Tobechi Nneji, Uriel Oputa, Ifeanyi Dike to star in BET Top Actor Africa - PM NEWS Nigeria" (in en-US). PM NEWS Nigeria. 2016-02-23. http://www.pmnewsnigeria.com/2016/02/23/tobechi-nneji-uriel-oputa-ifeanyi-dike-to-star-in-bet-top-actor-africa/.
- ↑ "Michelle Nini Blog - news-events-lifestyle-fashion and beauty". michelleniniblog.com. Archived from the original on 2016-03-04. Retrieved 2020-05-15.
- ↑ Anozim. "Star Focus: Tobechi Nneji (TobeDaDiva)". The Guardian Nigeria.
- ↑ "News : Nigerian VJ hopefuls take a step closer to TV stardom". MTV Base.
- ↑ "32 Hopefuls make it through to the Next Stage of the 2013 MTV Base Nigeria VJ Search - Banky W, Brymo, Funke Akindele & L.O.S at the Audition Event". BellaNaija.
- ↑ "The Next Titan – Nigeria’s First Business Reality TV Show". Newsdiaryonline.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2017-02-08. Retrieved 2020-05-15.
- ↑ "TheNET.ng - Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games". Nigerian Entertainment Today - Nigeria's Top Website for News, Gossip, Comedy, Videos, Blogs, Events, Weddings, Nollywood, Celebs, Scoop and Games (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-12-21.
- ↑ "BET Top Actor Africa: Meet Tobechi, Uriel, Dike, The Nigerian Contestants - Vanguard News" (in en-US). Vanguard News. 2016-03-07. http://www.vanguardngr.com/2016/03/bet-top-actor-africa-meet-tobechi-nneji-uriel-oputa-and-ifeanyi-dike-the-nigerian-contestants/.
- ↑ "Tobechi Nneji, Uriel Oputa, Ifeanyi Dike to star in BET Top Actor Africa - PM NEWS Nigeria" (in en-US). PM NEWS Nigeria. 2016-02-23. http://www.pmnewsnigeria.com/2016/02/23/tobechi-nneji-uriel-oputa-ifeanyi-dike-to-star-in-bet-top-actor-africa/.
- ↑ "Why is there so Much Pressure Leading Up to the 30s? WATCH this Trailer for an Insightful New Documentary "4th Decade" - BellaNaija". www.bellanaija.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2017-12-21.
- ↑ "MIZSUNSHINE GIST – Tobe DaDiva( @tobedadiva) Presents Her Bedroom Diaries". mizsunshine.com. Archived from the original on 2015-06-16. Retrieved 2020-05-15.
- All articles with dead external links
- Articles with dead external links from October 2023
- Articles with invalid date parameter in template
- Articles with permanently dead external links
- CS1 Èdè Gẹ̀ẹ́sì-language sources (en)
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- Nigerian radio personalities
- Madonna University (Ihiala) alumni
- University of Calabar alumni
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Nigerian television talk show hosts
- Igbo radio personalities
- Igbo television personalities
- People from Imo State
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1986
- Queen's College, Lagos alumni