Tonye Garrick

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Tonye
lóri NdaniTV
lóri NdaniTV
Background information
Orúkọ àbísọTamunotonye Nneka Nkiruka Ibiyemi Garrick
Ọjọ́ìbí27 Oṣù Kẹjọ 1983 (1983-08-27) (ọmọ ọdún 39)
England
Ìbẹ̀rẹ̀Lagos, Nigeria
Irú orin
Occupation(s)Singer-songwriter, fashion and interior designer
Instruments
  • Vocals
  • singing
Years active2010–present
LabelsMade Men
Associated acts
Websiteiamtonye.com

Tonye Garrick (tí a bí ní 27 August 1983) tí òpòlopò ènìyàn mò sí Tonye jẹ́ olorin ọmọ orílè-èdè Naijiria tí a bí bi sí orílè-èdè England. [1] Orin accapella rè pèlú akole "what about us?"(tí ó ko ní odun 2010) ni wọ́n lò níbi ìjíròrò Ààrẹ Ọ̀dọ́ Nàìjíríà lọ́dún 2011. [2] Ófi isé rè kalè gégé bi olubadamoran òwò ní odun 2013 láti bèrè orin kiko [3]

Àárò ayé àti èkó rè[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Tonye je omo abinibi ilu Benin ni Ipinle Edo, orílè-èdè Nàìjirià. Ìyá rè jé omobibi ìpínlè Anambra Ìyá agba rè ló fun lorukọ "Tamunotonye". Ó lo ilé-ìwé Vivian Fowler Memorial School àti Queens College ni Èkó níbi tí o ti pari èkó Sekondiri rè. [4] Ó tèsíwájú èkó rè ní yunifásitì ti Marymount

Àwon Ìtókasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Tonye Garrick: the singer getting Nigeria dancing". TRUE Africa. 2015-10-08. Retrieved 2022-04-06. 
  2. "Tonye Garrick biography, net worth, age, family, contact & picture". Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria. 2012-12-05. Retrieved 2022-04-06. 
  3. "Tonye Garrick". DBpedia. 1983-08-27. Retrieved 2022-04-10. 
  4. http://www.naijadeevas.com/2012/12/deeva-of-week-tonye-garrick.html. Retrieved 2022-04-06.  Missing or empty |title= (help)