Jump to content

Tourcoing

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Gbọ̀ngàn Ìlú Tourcoing

Tourcoing (ìpè Faransé: ​[tuʁ.kwɛ̃]) jẹ́ ìlú kan ní apá àríwá Fránsì, nítòsí ìlú Mouscron nílẹ̀ Bẹ́ljíọ̀m àti ìlú Roubaix. Agbègbè náà tóbi tó 15.19 km², tí àwọn ènìyàn inú rẹ̀ sí jẹ́ 93,974 nígbà ìkànìyàn ọdún 2013.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]