Toyin Bolaji Adegoke
Ìrísí
Toyin Bolaji Adegoke tí a bí ní ọjọ́ kẹrìnlélógún, osù Ògún, ọdún 1964 jẹ́ adájọ́ ilé-ẹjọ́ ìjọba àpapọ̀ ti orílẹ̀-èdẹ̀ Nàìjíríà[1]. Ìlú Ìbàdàn ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní wọ́n bí í sí.
Èkọ́.
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó ka ìwé mẹ́wàá rẹ̀ tán ní Ojuku Grammar School ní ọdún ní ọdún 1981[2]. Ó tẹ̀síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní fásítì Maiduguri, ní ìpínlẹ̀ Maiduguri lọ́dún 1987 láti kẹ́kọ̀ọ́ gboyè nínú ìmọ̀ èdè Gẹ̀ẹ́sì (English).
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "::::: Hon.Justice Toyin Bolaji Adegoke , Federal High Court Nigeria :::::". ::::: Welcome to the Official Website of Federal High Court Nigeria :::::. Archived from the original on 2022-09-07. Retrieved 2023-03-11.
- ↑ "Toyin Bolaji Adegoke". Wikidata. 1964-08-24. Retrieved 2023-03-11.