Àwọn Tuareg
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Tuareg)
Àpapọ̀ iye oníbùgbé |
---|
5.2 million [1] |
Regions with significant populations |
Niger: 1,720,000 (1998)
|
Èdè |
The Tuareg language(s) (Tamasheq, Tamajeq, Tamahaq) |
Ẹ̀sìn |
Ẹ̀yà abínibí bíbátan |
Àwọn Tuareg (bakanna bi Twareg tabi Touareg, Beriberi: Imuhagh) je awon eniyan Beriberi adaeran alarinka. Awon ni won poju ti won ungbe ni Sahara ni arin Ariwa Afrika.[2][3] Won pe ara won ni Kel Tamasheq tabi Kel Tamajaq ("Awon to unso Tamasheq"), Imuhagh, Imazaghan tabi Imashaghen ("eniyan Olominira"), tabi Kel Tagelmust, i.e., "Awon afaso boju".[4]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Africa | Q&A: Tuareg unrest". BBC News. 2007-09-07. Retrieved 2010-06-16.
- ↑ "Q&A: Tuareg unrest". BBC. 2007-09-07. http://news.bbc.co.uk/2/hi/africa/6982266.stm. Retrieved 2008-01-04.
- ↑ "Who are the Tuareg?". Smithsonian Institution. Archived from the original on 2011-09-27. Retrieved 2007-11-03.
- ↑ See Rodd 1926.