Uche Ogbodo
Ìrísí
Uche Ogbodo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kẹrin 1986 Ipinlẹ Enugu, Naijiria |
Iṣẹ́ | Oṣere |
Uche Ogbodo (tí a bí ní Oṣù Kaàrún Ọjọ́ 17, Ọdún 1986) jẹ́ òṣèré fíìmù àti olùgbéréjáde ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1]
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A bí Ogbodo ní Ìpínlẹ̀ Enúgu. Ìrìn-àjò Ogbodo sí Nollywood bẹ̀rẹ̀ lẹ́hìn ìpinnu bàbá rẹ̀ láti forúkọ rẹ̀ sílẹ̀ pẹ̀lú ẹgbẹ́ Actors Guild of Nigeria ní Ìpínlẹ̀ Enúgu.[2] Láti ìgbà eré àkọ́kọ́ rẹ̀ ní ọdún 2006, ó ti ṣe bẹ́ẹ̀ kópa nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fíìmù lẹ́hìn náà.[3]
Àṣàyàn eré rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Be My Val
- Family Romance
- Festac Town
- Forces of Nature
- Four Sisters
- Gamblers
- Girl Child (2018)
- Broken Pieces (2018)
- His Holiness
- His Last Action
- Honour My Will
- The Laptop
- Light Out
- Over Heat
- Ovy's Voice
- Power of Beauty
- Price of Fame
- Raging Passion
- Royal Palace
- Sacrifice for Marriage
- Simple Baby
- Spirit of Twins
- Turning Point
- Yankee Girls
- Mummy Why (2016)
- Commitment Shy
- Only Love
- Caught-up
Àwọn àmì ẹ̀yẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Ayẹyẹ | Ẹ̀bùn | Èsì | itọkasi |
---|---|---|---|---|
2015 | 2015 Fashion Icon Awards | Fashion Icon | Gbàá | [4] |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Sholola, Damilola (27 September 2014). "My marriage was full of lies – Uche". Vanguard Newspaper. http://www.vanguardngr.com/2014/09/reals-reasons-marriage-crashed/.
- ↑ "How I Lost My Virginity At The Age Of 20 – Actress Uche Ogbodo". The Sun Newspaper (African Spotlight). 26 September 2012. Archived from the original on 6 January 2017. https://web.archive.org/web/20170106020116/http://africanspotlight.com/2012/09/26/how-i-lost-my-virginity-at-the-age-of-20-actress-uche-ogbodo/.
- ↑ Njoku, Benjamin (11 February 2012). "Every part of my body is a selling point – Uche Ogbodo". Vanguard Newspaper. http://www.vanguardngr.com/2012/02/every-part-of-my-body-is-a-selling-point-uche-ogbodo/.
- ↑ Haliwud (5 November 2015). "Actress Uche Ogbodo Wins Award For Fashion Icon Of The Year". Information Nigeria. http://www.informationng.com/2015/11/actress-uche-ogbodo-wins-award-for-fashion-icon-of-the-year.html. Retrieved 2 May 2016.