Èdè Ulukwumi
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Ulukwumi language)
Olùkùmi | |
---|---|
Sísọ ní | Nàìjíríà |
Ọjọ́ ìdásílẹ̀ | 1992 |
Agbègbè | Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | 10,000 |
Èdè ìbátan | |
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-3 | ulb |
Olùkùmi (tàbí Ulukwumi, Ulukhwumi) jẹ́ èdè irú Yorùbá ní Nàìjíríà (ní Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà).[1]
Èdè Gẹ̀ẹ́sì | Èdè Olùkùmi | Èdè Yorùbá | Èdè Òwé | Èdè Igala |
---|---|---|---|---|
hand | ọwọ́ | ọwọ́ | ọwọ́ | ọwọ́ |
yam | usu | isu | usu/isu | uchu |
body | ara | ara | ọra | ọla |
child | ọma | ọmọ | ọmọ | ọma |
friend | oluku | ọ̀rẹ́ | olúku | ónùkú |
woman | obìnrin | obìnrin | obùnrin | ọ́bùlẹ |
father | ba | bàbá | baba | àtá |
person | ẹnẹ | ẹni | ọni | ọ́nẹ̀ |
fire | una | iná | uná | úná |
word | ọ̀fọ̀ | ọ̀rọ̀ | ọ̀rọ̀ | ọ̀là |
heart | ẹdọ | ọkàn | ẹ̀kẹ̀dọ̀ | ẹdọ |
pot | usa | ìsà | usà | ùchà |
cow | ẹla | malu | ẹlá | ẹla |
old person | arigbo | arúgbo | arígbó | ògìjo |
rat | eku | eku | eku | íkélékwu |
carry | gbe | gbé | gbe | né |
eat | zẹ | jẹ | jẹ | jẹ |
colanut | obì | obì | obì | obì |
water | omi | omi | omi | omi |
urine | ìtọ́ | ìtọ́ | ìtọ́ | ìtọ́ |
cotton | owu | owu | owu | owu |
stone | òkúta | òkúta | òkúta | òkúta |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Arokoyo, Bolanle Elizabeth. 2012. A Comparative Phonology of the Olùkùmi, Igala, Owe and Yoruba Languages. Paper presented for the International Congress "Towards Proto-Niger-Congo: Comparison and Reconstruction", Paris, 18-21 September, 2012. 10pp.