Jump to content

Yunifásítì ìlú Abùjá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti University of Abuja)
Fáṣítì Ìpínlẹ̀ Abuja.
Yunifásítì ìlú Abùjá

Yunifásítì ìlú Abùjá jẹ́ yunifásítì ní ìlú Abuja, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. A da Yunifasiti yìí kalẹ̀ ní ọdun 1988 [1] bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwon akẹ́kọ̀ọ́ àkókó ṣe ayeye ìwọlé ní odún 1990 tí ìṣẹ́ sì bẹ̀rẹ̀ ní odún náà .[1] Orúkọ adarí yunifásitì tí ìlú Abuja lọ́wọ́ ní Ọ̀jọ̀gbọ́n Lar Patricia Manko [2]. Yunifásitì Abújá ní ọgbà méjì(Main campus àti mini campus). Mini campus wà ni ìlú Gwagwalada, main campus sì wà ní ọ̀nà Àbújá-airpot. Yunifásitì ìlú Àbújá ní ilẹ̀ tí o kojá ẹgbẹ̀rún mọ́kànlá hectare (11, 000 hectares) èyi tí ó mú won jẹ́ yunifásitì kejì tí ó ní ilẹ̀ jù ní Nàìjíríà [3].

A da ile ikawe Yunifisiti naa kale ni odun 1988 lati gbaruku ti kiko,omimo ari iwadi eyiuti o je okan lara awon ete Yunifisiti ilu Abuja nipa pipese awon ohun ti akeko nilo fun eko ni lort ero ayejujara ati iwe ti eniyan le dimu.[4]

  1. 1 2 "About - University of Abuja". UNIABUJA. Archived from the original on 2022-03-01. Retrieved 2022-03-01.
  2. Report, Agency (2019-07-01). "University of Abuja gets new VC". Premium Times Nigeria. Retrieved 2022-03-01.
  3. Olusunle, Tunde (2021-11-20). "The Unilorin 'better by far' basket and one bad apple". TheCable. Retrieved 2022-03-02.
  4. "UNIVERSITY OF ABUJA LIBRARY's open resources | University of Abuja Open Education Resources (OER)". oer.uniabuja.edu.ng (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2022-12-30. Retrieved 2022-12-30.