Usman Jibrin

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Usman Jibrin (late)
Governor of North Central State, Nigeria
Lórí àga
30 July 1975 – 1977
Asíwájú Abba Kyari
Arọ́pò Muktar Muhammed
Personal details
Ọjọ́ìbí Àdàkọ:Birth year
Nasarawa, Nasarawa State, Nigeria
Aláìsí 8 September 2011(2011-09-08) (ọmọ ọdún 68–69)

Usman Jibrin (tí a bí ní ọdún 1942 tí ó sì kú ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹsàn-án ọdún 2011)[1] jẹ́ òṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Naijiria tí ó jẹ́ gómìnà ológun tí Ipinle Kaduna láti oṣù keje ọdún 1975 títí di ọdún 1977 lásìkò ìjọba ológun ti Murtala Mohammed.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]