Jump to content

Uzee Usman

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Use mdy dates

Uzee Usman
Uzee Usman on set for Taurarin Zamani
Ọjọ́ìbíUzee Usman Adeyemi
11 Oṣù Kọkànlá 1986 (1986-11-11) (ọmọ ọdún 38)
Kaduna, Kaduna State, Nigeria
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́film producer, actor, television presenter
Ìgbà iṣẹ́2003–present

Uzee Usman Adéyẹmí tí wọ́n bí ní ọjó Kọkànlá oṣù Kọkànlá ọdún 1986, jẹ́ Òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá, olùgbéré-jáde, adarí eré, òun ni ó gbé eré tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Oga Abuja jáde. [1]Ó jẹ́ òṣèré tí ó ní agbáea láti máa kópa nínú agbo Nollywood àti Kanywood lápapọ̀ láì fara gbọ́n ibìkan. Akitiyan yí sì ti fun ní ànfaní láti gba àwọn Amì-ẹ̀yẹ iríṣiríṣi bíi amì-ẹ̀yẹ Young Entrepreneur of the Year níọdún 2016 níbi ayẹyẹ "National Heritage Award".[2][3]

Usman ni ó jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Kwara, àmọ́ wọ́n tọ dàgbà ní Ìpínlẹ̀ Kàdúná, Ó ti kàwé gboyè nínú ẹ̀kọ́ ìmò nípa ìṣèlú àti ìmó̀ nípa èdè Gẹ̀ẹ́sì ní ilé-ẹ̀kọ́ Yunifásitì Àbújá àti Yunifásitì Jos ṣáájú kí ó tó lọ sí orílẹ̀-èdè South Africa láti tún lọ kọ́ ìmọ̀ síwájú si.

Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí aṣara-lóge ní ọdún 2003,[4] tí ó sì tún bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣíṣe ní àárín ọdún 2013. Ó ti gbé àwọn eré ọlọ́kan-ò-jọ̀kan eré tí ó ti gba àmì-ẹ̀yẹ jáde ní abẹ́ ilé-iṣẹ́ Kannywood àti Nollywood pẹ̀lú.[5]including Oga Abuja, which won Best Hausa Movie of the Year at the 2013 City People Entertainment Awards;[6] Ọ̀kan lára àwọn eré rẹ̀ tí ó gba àmì-ẹ̀yẹ Sinimá àgbéléwò tí ó dára jùlọ ní agbo Kannywood ní ọdún 2014 níbi ayẹyẹ "City People Entertainment Awards", tí wọ́n sì tún yàn fún àmì-ẹ̀yẹ "Eré tí àwòrán rẹ̀ dára jùlọ" níbi ayẹyẹ 2014 Nigeria Entertainment Awards ni Maja.[7]

Àwọn Àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Àmì-ẹ̀yẹ Ìsọ̀rí Eré\ Àbájáde
2008 Africa Movie Academy Awards Best Make up London Boy[8] Gbàá
2013 City People Entertainment Awards Best Movie of the Year - Kannywood Oga Abuja Gbàá
2014 Africa Magic Viewers Choice Awards Best Movie of the Year Oga Abuja Gbàá
2014 City People Entertainment Awards Best Movie of the Year - Kannywood Maja Gbàá
2016 African Hollywood Awards[9] Best Film Producer Oga Abuja Gbàá

Àwọn àṣàyàn eré rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Àkọ́lé Ipa tí ó kó Genre
2015 Oga Abuja Produced Drama
  2015 Maja Produced Drama
  2016 Dark Closet Produced Drama
  2016 Power of Tomorrow Produced Drama
2016 Hassana da Hussaina Produced Drama
  2015 Har da mijina Actor Drama
 2019 Muqabala (Season 1&2) Produced & Actor Drama
  2016 Red Line Produced Drama
Dear Affy Actor Drama
2017 If I am President Actor & Line Producer [10] Drama
2018 Lagos Real Fake Life Produced Drama
2018 Mustapha Actor Drama
2019 'Almost Perfect Actor Drama
  2019 Least Expected Produced & Actor Drama
  2019 Maimuna Produced & Actor Drama
  2018 Sharo Actor Drama
2020 Good Citizen Produced Drama

[11]


Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Lere, Mohammed (July 11, 2013). "Kannywood, Nollywood comedy, 'Oga Abuja,' now on sale". Premium Times. Retrieved February 13, 2018. 
  2. "PressReader.com – Connecting People Through News". www.pressreader.com. Retrieved February 14, 2018. 
  3. "Emeka Ike, Uzee Usman, others honoured at the national heritage award – COMPLETE ENTERTAINMENT". tvcontinental.tv. May 7, 2016. Retrieved February 14, 2018. 
  4. "Uzee: From makeup artist to film director". 24 April 2018. Retrieved 6 May 2020. 
  5. Lere Mohammed (January 11, 2014). "I brought John Okafor, Nkem Owoh to Kannywood – Usman Uzee". Retrieved February 13, 2018. 
  6. thenet (July 17, 2013). "Mary Uranta, Yul Edochie, Wizkid, Jackie Appiah, John Dumelo biggest winners at City People Awards". thenet.ng. Retrieved February 14, 2018. 
  7. Editor (25 November 2014). "Nigerian Entertainment Awards 2014". Pulse. Archived from the original on July 8, 2018. Retrieved 14 February 2018. 
  8. https://www.premiumtimesng.com/entertainment/153150-brought-john-okafor-nkem-owoh-kannywood-usman-uzee.html
  9. Lere, Mohammed (November 6, 2016). "Hadiza Gabon, Usman Uzee honoured at African Hollywood Awards". Premium Times. Retrieved February 13, 2018. 
  10. https://www.imdb.com/title/tt9189476/fullcredits
  11. "IMDb". Retrieved 5 May 2020. 

Àdàkọ:Authority control Àdàkọ:Nigeria-actor-stub _