Valentine
Ọjọ Valentine, ti wọn tun pe ni Ọjọ Saint Falentaini tabi ajọdun Falentaini,[1] ma n waye lọdọọdun ni oṣu keji ọjọ kerinla.[2] O pilẹṣẹ gẹgẹbi ọjọ ajọdun Kristiẹni ti o bu ola fun ọkan tabi meji awọn ajẹriku Kristiẹni akọkọ ti a npè ni Saint Valentine, nipasẹ aṣa eniyan oti di asa pataki, ẹsin, ati ayẹyẹ ife ni ọpọlọpọ awọn agbegbe ni agbaye.[3]
Orisirisi itan awon ajeriku ti o ni ṣe pẹlu ọpọlọpọ awọn Falentaini ni o sopọ mo ọjọ kerinla, oṣu keji[4] lara re ni itan gbigbe sẹwọn ti Saint Falentaini ti Rome fun iṣẹ iranṣẹ si awọn Kristiani ti won se ijiya fun labẹ Ijọba Romu ni ọrundun kẹta[5][6] Gẹgẹbi ironyin atọwọdọwọ, Saint Falentaini se iwosan fun ọmọbirin afọju onitubu re.[7] Ọpọlọpọ awọn afikun nigbamii se arosọ ti o dara julọ ni ibatan si akori ifẹ: aroso pataki ni ọrundun mejidilogun sọ pe o kọ leta ranse si ọmọbirin afọju onitubu re ti o fowo si wipe “Emi ni Falentaini rẹ” gẹgẹbi idagbere ṣaaju ki won to pa; aroso miiran so wipe Saint Falentaini maa n ṣe igbeyawo fun awọn ọmọ-ogun Kristiẹni ti o jẹ ewọ fun lati ṣe igbeyawo.[8]
Ọ tún le ka
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Chambers 21st Century Dictionary, Revised ed., Allied Publishers, 2005 ISBN 9780550142108.
- ↑ "Valentine’s Day - Definition, History, & Traditions". Encyclopedia Britannica. December 14, 2021. Retrieved February 14, 2022.
- ↑ "St. Valentine, the Real Story". CBN.com - The Christian Broadcasting Network. September 25, 2013. Retrieved February 14, 2022.
- ↑ Ansgar, 1986, Chaucer and the Cult of Saint valentine, pp. 46–58.
- ↑ Cooper, J.C. (October 23, 2013). Dictionary of Christianity. Routledge. p. 278. ISBN 9781134265466.
- ↑ Chryssides, George D.; Wilkins, Margaret Z. (2014). Christians in the Twenty-First Century. Routledge. ISBN 978-1-317-54557-6.
- ↑ Ball, Ann (January 1, 1992). A Litany of Saints. OSV. ISBN 9780879734602.
- ↑ Chryssides, George D.; Wilkins, Margaret Z. (2014). Christians in the Twenty-First Century. Routledge. ISBN 978-1-317-54557-6.