Victor Osimhen
Appearance
Personal information | |||
---|---|---|---|
Orúkọ | Victor James Osimhen | ||
Ọjọ́ ìbí | 29 Oṣù Kejìlá 1998 | ||
Ìga | 1.86 m | ||
Playing position | Forward | ||
Club information | |||
Current club | Lille | ||
Number | 7 | ||
Youth career | |||
–2017 | Ultimate Strikers Academy | ||
Senior career* | |||
Years | Team | Apps† | (Gls)† |
2017–2019 | VfL Wolfsburg | 12 | (0) |
2018–2019 | → Charleroi (loan) | 34 | (19) |
2019 | Charleroi | 0 | (0) |
2019– | Lille | 18 | (10) |
National team‡ | |||
2015 | Nigeria U17 | 7 | (10) |
2015 | Nigeria U20 | 4 | (3) |
2017– | Nigeria | 9 | (4) |
* Senior club appearances and goals counted for the domestic league only and correct as of 6 December 2019. † Appearances (Goals). |
Victor James Osimhen tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kọkàndínlọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 1989 (29th December 1998) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà agbábọ́ọ̀lù ṣiṣẹ́ ikọ̀ agbábọ́ọ̀lù Lille tí orílẹ̀ èdè France. Òun ni agbaboolu sáwọ̀n tó dára jù lọ fún ikọ̀ rẹ̀ lọ́wọ́́lọ́wọ́.[1] [2] [3] [4] Ní ọdún 2020, wọ́n tari Osimhen lọ sí inú ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù Napoli nínú ìdíje Serie A club pẹ̀lú iye owó tí ó tó €70 million.
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Osimhrn ní Ìpínlẹ̀ Èkó nígbà tí awọn òbí rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí Ìpínlẹ̀ Edo. Osimhen fẹ́ràn kí ó ma gbá bọ́ọ̀lù aláfẹsẹ̀gbá látàrí wípé ó fẹ́ di ẹlẹ́sẹ̀ ayò bí gbajú-gbajà agbá bọ́ọ̀lù ọmọ orílẹ̀-èdè Côte d'Ivoire ìyẹn Didier Drogba.[5]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Àdàkọ:Worldfootball.net
- ↑ "Wolfsburg in deal for young Nigerian Victor Osimhen". BBC Sport. 2017-01-01. Retrieved 2020-01-05.
- ↑ "Victor Osimhen - Player profile 19/20". Transfermarkt (in Èdè Jámánì). Retrieved 2020-01-05.
- ↑ "Victor Osimhen Archives - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. Retrieved 2020-01-05.
- ↑ "Didier Drogba is my idol - Nigeria U17 striker Victor Osimhen". ESPN. 28 October 2015. Retrieved 21 February 2021.