Wólíì Àrólé
Ìrísí
Wólíì Àrólé Eni tí orúkọ àbísọ rẹ̀ ń jẹ́ Olúwatóyìn Báyégùn ni wọ́n bí ní Ìlú Ìkàrẹ́-Àkókó ní ìpínlẹ̀ Òndó. Jẹ́ òṣèré Orí ìtàgé àti adẹ́rínpòṣónú ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà.[1][2]
Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Olúwatóyìn lọ sí Ilé-ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ yi Olápàdé Àgòrò tí ó wà ní Àpáta ní ìlú Ìbàdàn, tí ó si lọ sí Ilé-ẹ̀kọ́ Girama Government College. Bákan náà ni ó lọ sí Ilé-ẹ̀kọ́ Ifáfitì Obáfẹ́mi Awólọ́wọ́ níbi tí ó ti gba ìwé ẹ̀rí nínú ìmọ̀ Psycology.[3] [4]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "arole biography". Google Search. Retrieved 2019-12-14.
- ↑ "Woli Arole Bio - Age & 7 Other Things You Don't Know About Him". 360dopes. 2019-01-21. Retrieved 2019-12-14.
- ↑ "How I found fame on Instagram – Comedian, Woli Arole". Premium Times Nigeria. 2017-09-30. Retrieved 2019-12-14.
- ↑ Bada, Gbenga (2018-12-31). "Woli Arole, Frank Donga, Kelvin Ikeduba attend 'The Call' premiere". Pulse Nigeria. Retrieved 2019-12-14.