Wale Ogunyemi
Wale Ogunyemi | |
---|---|
Ọjọ́ìbí |
12 August 1939 Osun State, Nigeria. |
Aláìsí | December 2001 |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | playwright |
Years active | 1963–present |
Known for |
The Lion and the Jewel Kongi's Harvest Sango Langbodo[1] |
Oloye Wale Ogunyemi, OFR (ojo kejila osu kejo odun 1939 si osu kejila odun 2001) je omo bibi ilu Naijiria, o si je ogbontarigi elere ori itage, ere fiimu, onkowe to pegede ati akomolede Yoruba[2]
Ibere Igbesi Aye[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
A bi i ni osu kejo odun 1939 ni Igbajo, okan lara awon ilu ti o wa ni Ipinle Osun, ni guusu-iwo oorun Naijiria.[3] O lo si ile eko giga Fasiti ti ilu Ibadan ni odun 1967 fun eko odun kan lori ere itage, ni odun kanna, ni won yan si ipo amugbalegbe oluwadi agba ni Ile-iwe eko nipa ile Afirika nibi ti o ti sise titi ti o fi feyin.[4][5][6]
Ise[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
O bere ise re gegebi elere ori-itage to k'oju osuwon ni ile-ise amohunmaworan ti iha iwo-oorun Naijiria ni ibere awon odun 1960.[7] Leyin eyi, o sise po pelu ojogbon Wole Soyinka, eni ti o ni ami eye Nobel Laureate ati pe o di okan lara awon omo egbe ti o je ipile fun egbe elere ori itage Soyinka Orisun.[8] Awon ise re ti o se mu yangan ni o so di aayo fun oniruuru ipa ti o ko gege bi "Bale" ninu The Lion and the Jewel[9] ati Dende ninu Kongi's Harvest lati owo ojogbon Wole Soyinka.[10] O tun farahan ninu The Beatification Of Area Boy, ere ti a ti owo Wole Soyinka ko, ti a si se afihan re fun igba akoko ni West Yorkshire Playhouse ni odun 1995.[11] O da opolopo ere ori itage ko, o si tun ko opolopo pelu ifowosowopo pelu awon elomiran ki o to ku ni osu kejila odun 2001.[12][13]
Awon itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
- ↑ "Set to battle demons on mount Langbodo". The Punch - Nigeria's Most Widely Read Newspaper. Retrieved 18 January 2015.
- ↑ Black African Literature in English, 1997-1999. https://books.google.nl/books?id=rAUbyu1wRCsC&pg=PA312&lpg=PA312&dq=Wale+Ogunyemi,+script+writer&source=bl&ots=vkzFLVY14G&sig=ZyxxjKFasOKrFvpo0npZSJR4eos&hl=en&sa=X&ei=ZX-7VJz-FMf6PM2YgeAE&ved=0CBAQ6AEwAg. Retrieved 18 January 2015.
- ↑ Ọdún. https://books.google.com.ng/books?id=9PsbR01ZUTAC&pg=PA24&lpg=PA24&dq=Wale+Ogunyemi,+a+writer+of+all+time&source=bl&ots=7IagELpJfm&sig=yg9LmdMiTlIAHqCemhWa6l6tup8&hl=en&sa=X&ei=ENK7VPHQKsXgOMa_gYgB&redir_esc=y. Retrieved 18 January 2015.
- ↑ European-language Writing in Sub-Saharan Africa. https://books.google.nl/books?id=D6PrqVKaZtgC&pg=PA774&lpg=PA774&dq=Wale+Ogunyemi,+script+writer&source=bl&ots=JCZr5Atl3B&sig=OaU3ILAvvZItUgqLABwTbmaIJ4w&hl=en&sa=X&ei=ZX-7VJz-FMf6PM2YgeAE&ved=0CBUQ6AEwBA. Retrieved 18 January 2015.
- ↑ Relocating Agency. https://books.google.nl/books?id=RTzibTsqLE4C&pg=PA206&lpg=PA206&dq=Langbodo+by+Wale+Ogunyemi&source=bl&ots=LGSxVo-WSF&sig=i9YjPPGBwJUb6Z3J67vs32m81xw&hl=en&sa=X&ei=AtW7VIOcJYfvOdGogfgJ&ved=0CAsQ6AEwADgU. Retrieved 18 January 2015.
- ↑ The Columbia Guide to West African Literature in English Since 1945. https://books.google.nl/books?id=VaZx0Q2O3l8C&pg=PA150&lpg=PA150&dq=Langbodo+by+Wale+Ogunyemi&source=bl&ots=k9MdiBPLed&sig=g8ucXOyOEHd_eZz1w4o3eNCBA1I&hl=en&sa=X&ei=AtW7VIOcJYfvOdGogfgJ&ved=0CBsQ6AEwBjgU. Retrieved 18 January 2015.
- ↑ "The Nostalgic Drum". google.nl. Retrieved 18 January 2015.
- ↑ "WHY WALE OGUNYEMI STILL LIVES ON NIGERIA'S STAGE-DIRECTOR OF LANGBODO". thenigerianvoice.com. Retrieved 18 January 2015.
- ↑ Who's Who in Contemporary World Theatre. https://books.google.nl/books?id=dJSFAgAAQBAJ&pg=PA227&lpg=PA227&dq=Wale+Ogunyemi+featured+in+The+lion+and+the+jewel&source=bl&ots=XiWZXOFjaB&sig=2gauiC_ZAfPIU7Me3lgmDfjSHvg&hl=en&sa=X&ei=z4G7VIjnM4GdPemXgNAJ&ved=0CA4Q6AEwAQ. Retrieved 18 January 2015.
- ↑ Childhood in African Literature. https://books.google.nl/books?id=WEArQ7PQgw4C&pg=PA140&lpg=PA140&dq=Wale+Ogunyemi,+script+writer&source=bl&ots=2_lRB8TSL1&sig=gsRkyybFSi3tF68DxbquPaf4wt0&hl=en&sa=X&ei=6oC7VNztMszjO768gZgB&ved=0CCEQ6AEwBzgK. Retrieved 18 January 2015.
- ↑ "Obituary: Wale Ogunyemi". the Guardian. Retrieved 18 January 2015.
- ↑ Fertile Crossings. https://books.google.com.ng/books?id=9KhDYdn6myMC&pg=PA215&lpg=PA215&dq=Wale+Ogunyemi,+a+writer+of+all+time&source=bl&ots=umCpdvTR2P&sig=tD9mg6i4eVcuOKBv2T0dFAA5JRk&hl=en&sa=X&ei=ENK7VPHQKsXgOMa_gYgB&redir_esc=y. Retrieved 18 January 2015.
- ↑ "Student Encyclopedia of African Literature". google.nl. Retrieved 18 January 2015.