Walter Raleigh
Appearance
Sir Walter Raleigh | |
---|---|
Iṣẹ́ | Writer, poet, soldier, courtier, explorer |
Walter Raleigh A bi i ni 1552. O ku ni 1618. Soja omo ile Geesi ni o si maa n rin irinajo pupo. Oun ni o mu taba wa si ile Geesi ti o si mu 'potato' wa si Ireland. Oun ati Sir Humphrey Gilbert (ti o je half-brother) ni won jo ja ni ile Amerika. O tun ja fun ile Geesi ni Ireland. Iwe History of the World ti o ko ko pari re titi ti o fi ku. Won pa a ni nitori pe ko pa ofin mo.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |