Walter Sisulu
Walter Max Ulyate Sisulu | |
---|---|
Secretary-General of the African National Congress | |
In office 1949–1954 | |
Asíwájú | James Arthur Calata |
Arọ́pò | Oliver Tambo |
Deputy President of the African National Congress | |
In office July, 1991 – 1994 | |
Asíwájú | Nelson Mandela |
Arọ́pò | Thabo Mbeki |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Engcobo, Transkei (now Eastern Cape), South Africa | Oṣù Kàrún 18, 1912
Aláìsí | May 5, 2003 | (ọmọ ọdún 90)
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | African National Congress |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Albertina Sisulu |
Walter Max Ulyate Sisulu (May 18, 1912 – May 5, 2003) je alakitiyan olodi apartheid ara Guusu Afrika ati omo egbe Kongresi Omoorile-ede Afrika (ANC).
Won bi ni Engcobo to wa ni Transkei (to je apa Eastern Cape Province, Guusu Afrika loni). Iya re Alice Sisulu je olutoju ile, baba re, Victor Dickenson, je alawofunfun osise ijoba. [1] O kuro ni Engcobo leyin eko re ni 1926, o si ko o si Johannesburg ni 1928 nibi to ti se orisirisi ise. O di omo egbe ANC ni 1940. Ni 1943, pelu Nelson Mandela ati Oliver Tambo, o di omo egbe ANC Youth League, ti Lembede dasile, to je akopo fun nibere. He later distanced himself from Lembede after Lembede (died 1947) had ridiculed his parentage (Sisulu was the son of a white foreman). Sisulu was a brilliant political networker and had a prominent planning role in the militant Umkhonto we Sizwe ("Spear of the Nation"). He was made secretary general of the ANC in 1949, displacing the more passive older leadership, and held that post until 1954.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Walter Sisulu - A Brief Biography Archived 2010-04-29 at the Wayback Machine. ANC