Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 21 Oṣù Keje
Ìrísí
- 1969 – Neil Armstrong ati Edwin "Buzz" Aldrin di awon eniyan akoko to fese te ori Osupa, nigba iranlosise Apollo 11.
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1899 – Ernest Hemingway, olukowe ara Amerika (al. 1961)
- 1923 – Rudolph A. Marcus, Canadian chemist, Nobel laureate
- 1951 – Robin Williams, osere/alawada ara Amerika (al. 2014)
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1967 – Albert Lutuli, oloselu ara Guusu Afrika
- 2004 – Edward B. Lewis, American geneticist, Nobel Prize in Physiology or Medicine laureate (b. 1918)