Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 25 Oṣù Keje
Ìrísí
- 1907 – Korea di ilẹ̀-onídàábòbò orílẹ̀-èdè Japan.
- 1920 – Ifiẹ̀rọbánisọ̀rọ̀: ìkéde radio àkọ́kọ́ lókè òkun wáyé.
- 1943 - Wọ́n ṣe ìrọ́pò Benito Mussolini pẹ̀lú Pietro Badoglio ní Itálíà.
- 2007 – Pratibha Patil (foto) di obìnrin àkọ́kọ́ tó jẹ Ààrẹ ilẹ̀ India.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1848 – Arthur Balfour, 33rd Prime Minister of the United Kingdom (d. 1930)
- 1941 – Emmett Till, American lynching victim (d. 1955)
- 1955 – Iman, Somalian-English model and actress
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1794 – André Chénier, French writer (b. 1762)
- 1826 – Kondraty Fyodorovich Ryleyev, Russian poet and revolutionary (b. 1795)
- 1834 – Samuel Taylor Coleridge, English poet (b. 1772)