Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 23 Oṣù Kẹ̀sán
- [[]]
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1863 – Mary Church Terrell, alakitiyan eto arailu ara Amerika (al. 1954)
- 1923 – Babs Fafunwa, olukoni ati alakoso eto eko ara Naijiria (al. 2010)
- 1926 – John Coltrane, afọnfèrè sáksófóónù ará Amẹ́ríkà (al. 1967)
- 1930 – Ray Charles, olórin ará Amẹ́ríkà (al. 2004)
- 1972 – Jermaine Dupri, atọ́kùn orin ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1939 – Sigmund Freud, olùtọ́júòyè-ọkàn ará Austríà (ib. 1856)
- 1973 – Pablo Neruda, akọewì ará Tsílè (ib. 1904)