Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 25 Oṣù Kẹ̀sán
Appearance
- [[]]
- [[]]
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1897 – William Faulkner, onkọ̀wé ará Amẹ́ríkà (d. 1962)
- 1911 – Eric Williams, ọkùnrin orílẹ̀-èdè Trinidad àti Tobago (d. 1981)
- 1968 – Will Smith, Òṣeré àti olórin ara Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 2003 – Edward Said, Àlarìwisi mọọkọmọọka tí ará ìlú Palestine (b. 1935)
- 2011 – Wangari Maathai, alápọn àyíká àti olóṣèlú tí ìlú Kenya (b. 1940)