Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 26 Oṣù Kẹ̀sán
Appearance
- 1984 – Orile-ede Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan gbà láti fi Hong Kong sílẹ̀.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1889 – Martin Heidegger, amòye ará Jẹ́mánì (al. 1976)
- 1936 – Winnie Mandela (fọ́tò), alákitiyan alòdìsí ápátáìd ará Gúúsù Áfríkà
- 1981 – Serena Williams, agbá tẹnís ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1937 – Bessie Smith, akọrin ará Amẹ́ríkà (ib. 1894)
- 1952 – George Santayana, amòye ará Spéìn (ib. 1863)
- 2008 – Paul Newman, òṣeré ará Amẹ́ríkà (ib. 1925)