Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 24 Oṣù Kẹfà
Ìrísí
- 1692 – Ìdásílẹ̀ ìlú Kingston (àwòrán), ní Jamáíkà.
- 2007 – Gordon Brown rọ́pò Tony Blair bíi Alákóso Àgbà ilẹ̀ Brítánì.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1846 – Samuel Johnson, alufa ati akoitan omo Yoruba (al. 1901)
- 1883 – Victor Franz Hess, ẹlẹ́bùn Nobel ará Austria (al. 1964)
- 1941 – Julia Kristeva, amòye ọmọ Bulgaria ará Fránsì
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1398 – Hongwu Emperor, olùdásílẹ̀ Ìran-Ọba Ming ní Ṣáínà (ib. 1328)
- 1908 – Grover Cleveland, Ààrẹ 22k àti 24k Orílẹ̀-èdè Amẹ́rííà (ib. 1837)
- 1931 – Xiang Zhongfa, Olórí Ẹgbẹ́ Kọ́múnístì Ṣáínà (ib. 1880)