Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 26 Oṣù Kàrún

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Pam Grier
Pam Grier

Ọjọ́ 26 Oṣù Kàrún: Ọjọ́ ÌlómìniraGeorgia(1918) àti Guyana (1966)

  • 1983Ìmínlẹ̀ kíkan ìtóbi iye 7.7 ṣẹlẹ̀ ní Japan, èyí fa tsunami, tó fa ikú pa ènìyàn 104 àti tó pa ẹgbẹẹ̀gbẹ̀rún ènìyàn lára.
  • 2008Àgbàrá ṣẹlẹ̀ ní apáìlàòrùn àti apágúsù Ṣáínà tó fa ikú ènìyàn 148 tó sì jẹ́ kí àwọn ènìyàn 1.3 ó kúrò nílé wọn.

Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...

  • 1926Miles Davis, afọnfèrè, olórí ẹgbẹ́-alùlù àti akórinjọ ará Amẹ́ríkà (al. 1991)
  • 1929J.F. Ade Ajayi, akọìtàn ará Nàìjíríà (al. 2014)
  • 1949Pam Grier (foto), òṣeré ará Amẹ́ríkà

Àwọn aláìsí lóòní...

Ọjọ́ míràn: 2425262728 | ìyókù...