Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 28 Oṣù Kàrún
Ìrísí
- 1936 – Alan Turing fi On Computable Numbers sílẹ̀ fún ìtẹ̀jáde.
- 1964 – Ìdásílẹ̀ Àgbájọ Ìtúsílẹ̀ Palẹstínì.
- 1975 – Àwọn orìlẹ̀-èdè mẹ́ẹ̀dógún Ìwọ̀òrùn Áfríkà tọwọ́bọ̀wé sí Àdéhùn ìlú Èkó láti ṣèdásílẹ̀ Àgbàjọ Òkòwò àwọn Orílẹ̀-èdè Ìwọòrùn Áfríkà (Àsìá).
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1912 – Patrick White, olùkọ̀wé ará Australíà (al. 1990)
- 1936 – Betty Shabazz, Alákitiyan ará Amẹ́ríkà (al. 1997)
- 1944 – Gladys Knight, akọrin R&B àti soul ará Amẹ́ríkà
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1953 – Hori Tatsuo, olùkọ̀wé ará Japan (ib. 1904)
- 2003 – Ilya Prigogine, aṣiṣẹ́olóògùn ará Bẹ́ljíọ̀m (ib. 1917)
- 2010 – Gary Coleman, òṣeré ará Amẹ́ríkà (ib. 1968)
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́. See the protection policy and protection log for more details. If you cannot edit this ojúewé and you wish to make a change, you can submit an edit request, discuss changes on the talk page, request unprotection, log in, or create an account. |