Alan Turing

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Alan Turing
Alan Turing
Ìbí(1912-06-23)23 Oṣù Kẹfà 1912
Maida Vale, London, England, United Kingdom
Aláìsí7 June 1954(1954-06-07) (ọmọ ọdún 41)
Wilmslow, Cheshire, England, United Kingdom
IbùgbéUnited Kingdom
Ọmọ orílẹ̀-èdèBritish
PápáMathematics, Cryptanalysis, Computer science
Ilé-ẹ̀kọ́University of Cambridge
Government Code and Cypher School
National Physical Laboratory
University of Manchester
Ibi ẹ̀kọ́King's College, Cambridge
Princeton University
Doctoral advisorAlonzo Church
Doctoral studentsRobin Gandy
Ó gbajúmọ̀ fúnHalting problem
Turing machine
Cryptanalysis of the Enigma
Automatic Computing Engine
Turing Award
Turing Test
Turing patterns
Àwọn ẹ̀bùn àyẹ́síOfficer of the Order of the British Empire
Fellow of the Royal Society

Alan Mathison Turing, OBE, FRS (play /ˈtjʊərɪŋ/ TEWR-ing; 23 June 1912 – 7 June 1954), je ara Ilegeesi onimomathimatiki, onimo ogbon, aseatuwoipamo ati asesayensi komputa. O ko ipa pataki ninu idagbasoke sayensi komputa, nipa pipese isodimudaju awon itumo "algoritmu" ati "isiropo" ("computation") pelu ero Turin, to kopa pataki ninu idasile komputa odeoni.[1] Turing je gbigba bi baba sayensi komputa ati laakaye afowoda.[2]


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid <ref> tag; no text was provided for refs named AFP
  2. Homer, Steven and Alan L. (2001). Computability and Complexity Theory. Springer via Google Books limited view. p. 35. ISBN 0-3879-5055-9. http://books.google.com/?id=r5kOgS1IB-8C&pg=PA35. Retrieved 2011-05-13.