Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 6 Oṣù Kẹrin
Ìrísí
- 1782 – Rama I ile Siam (orile-ede Thailand) sedasile idile-oba Chakri.
- 1896 – Ni ilu Athens, ajoyo ibere awon Idije Olimpiki ode-oni waye.
- 1994 – Ipa-eyarun ara Ruwanda bere nigbati baalu to ungbe aare Rwanda, Juvénal Habyarimana ati aare Burundi, Cyprien Ntaryamira je jiju jabo sile.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1935 – John Pepper Clark, olukowe ara Naijiria
- 1937 – Billy Dee Williams, osere ara Amerika
- 1963 – Rafael Correa, aare ile Ekuado
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1992 – Isaac Asimov, olukowe omo Russia (ib. 1920)
- 1994 – Juvénal Habyarimana, aare ile Ruwanda (ib. 1937)
- 1994 – Cyprien Ntaryamira, aare ile Burundi (ib. 1956)