Jump to content

Wikipedia:Àwọn ìlànà dídẹrùn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Ohunkóhun tí ẹ bá ṣe nínú Wikipedia di apá rẹ̀. Kò ṣe é ṣe kí a mọ́ ṣe àṣìṣe sùgbọ́n tí ẹ bá tẹ̀lé àwọn ìlànà ìsàlẹ̀ wọ̀nyí ẹ le yà fún wọn:

  1. Ẹ mọ́ fòyà láti ṣàtúnṣe àwọn ojúewé. Ẹ gba àwọn elòmíràn náà níyànjú láti kópa, bótilẹ̀jẹ́pé ẹ lè yari sí ara yín. Ẹ gbà wọ́n níyànjú pé kí wọn ó mọ́ fòyà láti ṣàtúnṣe!
  2. Ẹ wùwà bíi ọmọlúàbí sí àwọn oníṣe míràn.