Wikipedia:Àwọn oníṣe Wikipedia
Appearance
Àwọn oníṣe Wikipedia ni àwọn oníṣe tí wọ́n ń ṣàfikún sí orí Wikipedia.
Àwọn oníṣe Wikipedia ní ẹ̀tọ́:
- Láti kọ sínú gbogbo àwọn ojúewé
- Láti dá àwọn ojúewé tuntun
- Láti tóka sí àwọn ojúewé tí wọn ń fẹ́ ìparẹ́
- Láti pa gbogbo àwọn àkóónú àwọn ojú ewé rẹ́
Àwọn oníṣe Wikipedia tí wọ́n ti forúkọ sílẹ̀ ní ẹ̀tọ́ sí:
- Láti kọ sínú àwọn ojú ewé títìpa díẹ̀
- Láti ní ojú ewé fún ara wọn àti àwọn ìfọ̀rọ̀wérọ̀ wọn. Ẹ wo inú Wikipedia:Ojú ewé oníṣe fún kíni àwọn ohun tí wọ́n jẹ́ ẹ́tọ́ àti àwọn ohun tí kò jẹ́ èwọ̀ níbẹ̀ (àwọn ojúewé yìí náà le jẹ́ títúnṣe lọ́wọ́ àwọn ẹlòmíràn).
Àwọn ẹ̀tọ́ pàtàkì bi títì pa àwọn ojú ewé àti dídínà àwọn oníṣe jẹ́ ti àwọn olùmójútò.