Wikipedia:Ṣé ẹ mọ̀ pé...
Ìrísí
Ṣé ẹ mọ̀ pé...
- ... Ada Lovelace (àwòrán) jẹ́ gbígbà bi atòlànà kọ̀mpútà àkọ́kọ́ nínú ìtàn Ìṣiṣẹ́ kọ̀mpútà?
- ... pẹ̀lú goolu 37 Rashidi Yekini ni agbábọ́ọ̀lù tó ní goolu jùlọ fún Nàìjíríà?
- ... Anwar el Sadat ni olórí àwọn Arab àkọ́kọ́ tó ṣèdámọ̀ Israel bi orílẹ̀-èdè?
- ... Bill Gates àti Paul Allen ni wọn dá ilé-iṣẹ́ kọ̀mpútà Microsoft sílẹ̀ ní 1975?
Ẹ le dá àbá nípa Ṣé ẹ mọ̀ pé... ojowaju níbí Àwọn tó hàn tẹ́lẹ̀ wà níbí |
ojúewé yìí ti jẹ dídá àbò bò láti ṣàtúnṣe sí. See the protection policy and protection log for more details. Please discuss any changes on the talk page; you may submit an edit request to ask an administrator to make an edit if it is uncontroversial or supported by consensus. You may also request that this page be unprotected. |