Yerima Lawal Ngama
Ìrísí
Yerima Lawal Ngama je olóṣèlú ọmọ orílè-èdè Nàìjíríà lati Ìpínlẹ̀ Yobe ni Naijiria . [1]
Yerima Lawal Ngama ti jẹ minisita fun ètò ìnáwó fun ijọba Naijiria. O tun je oludije gómìnà labẹ ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party . [2] [3]