Yunifásítì ìlú Èkó
Yunifásítì ìlú Èkó University of Lagos | |
---|---|
Motto | In deed and in truth. |
Established | 1962 |
Type | Public |
President | Prof Tolu Olukayode Odugbemi |
Location | Lagos, Nigeria |
Campus | Urban |
Website | www.unilag.edu.ng |
Yunifásítì ìlú Èkó (University of Lagos tàbí UNILAG) jé fásitì ìjọba àpapò ni Naijiria tó bùdó si ilu Èkó.
Ìtàn yunifásítì ìlú Èkó
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]A dá UNILAG silẹ ni ọdún 1962, ọdún méjì lẹ́yìn òmìnira Naijiria independence of Nigeria láti ọwó àwọn Britain. Ó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn yunifásítì márùn-ún tí a dá lè ní orílè-èdè Nàìjíríà, tí a mò sí "first generation universities".[1][2] Eni Njoku ni a yàn gẹ́gẹ́ bí alákòóso àkọ́kọ́ ní yunifásítì ní ọdún 1962, èyí tí ọ́ ṣe títí di ọdún 1965 tí a sì ni ipò pada pẹ̀lú Saburi Biobaku. síbẹ̀síbẹ̀, nítorí àwọn àríyànjiyàn nípa bí a sè yàn sí ipò , ọ̀gbẹ́ni Kayode Adams gún Saburi pa , akẹ́kọ̀ọ́ tí ó gbàgbọ́ pé ááyan Saburi nítorí ẹyà ti ọ sí bójú mu.[3]
Láti ọdún 2017 [4] Títí di ojo òní , igbakeji olórí ni ọ̀jọ̀gbọ́n Oluwatoyin Ogundipe.ni ọdún 2019, Telifísàn BBC sọ̀rọ̀ nípa "female reporters were sexually harassed, propositioned and put under pressure by senior lecturers at the institutions – all the while wearing secret cameras".[5][6] yíyọ àwọn obìrin oníròyìn lẹ́nu lórí ìbálópọ̀ àti ìfúgunmọ́ láti ọwọ́ àwọn olùkọ́ àgbà ní yunifásítì ní àwọn ilé-ìwé - láti ìgbà yìí wa ni wọ́n gbé kámẹ́rà pamọ́ sára.
Yunifásítì tí gbé oríṣiríṣi ọ̀jọ̀gbọ́n tí ó yanrantí jáde nínú ìmọ̀ síyẹ́ǹsì, òṣèlú, amòfin, àwọn oníṣòwò ńlá , òǹkọ̀wé, àwọn eléré ìdárayá, àwọn ọba, ìmọ̀-ẹ̀rọ,ti ìlú Nàìjíríà àwọn olóye gbogbo , àti àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ilé ìwe mìíràn pẹ̀lú . Ni oṣù kẹsàn-án ọdún 2020, ọ̀kan lára àwọn nobel laureate àti ọ̀kan lára Pulitzer prize laureate ni wọ́n kà gẹ́gẹ́ bí i ọmọ ilẹ́ ìwé yunifásítì ìlú Èkó , ọmọ ilẹ́ ìwé, olùkọ́, tàbí òṣìṣẹ́.
Ìran
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Láti jẹ ile ẹkọ tó Dára jù lọ nínú títà yo imo, ìwà ati rí ran àwon eniyan lowo.[7]
Iṣẹ
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Láti ṣe ibùgbé tí ó dára fún ẹ̀kó, ìwé kika, Ìwádìí àti ìdàgbàsókè, níbití òṣìṣẹ́ àti akẹ́kọ̀ọ́ yóò ní Àjosepò tó dán mọ́rán láti kojú ẹlẹ́gbẹ́ won ni gbogbo àgbáyé [8]
Ile kíkọ ati Arabara
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]-
Research_and_innovation_office,_University_of_Lagos
-
Faculty_of_Art,_University_of_Lago
-
University_Library,_University_of_Lagos
-
J._P_Clark_Center,_University_of_Lagos
-
Sport_center,_University_of_Lagos
-
Unilag_Senate_house
-
Akintunde_Ojo_memorial_hall,_Unilag
-
Unilag_Lagoon_Front_Fountain
-
Quadrangle,_Faculty_of_Arts,_Unilag
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
- ↑ "Nigerian Education Profile". United States Diplomatic Mission to Nigeria. Archived from the original on 17 March 2010. Retrieved 15 October 2013. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "University of Lagos (1962- ) •". 10 December 2011.
- ↑ "Saburi Biobaku: Unilag's VC who was stabbed by a student who disagreed with his choice as VC". 4 February 2018.
- ↑ "Ambode Congratulates New UNILAG VC, Prof Oluwatoyin Ogundipe". 30 October 2017. Archived from the original on 4 June 2020. Retrieved 25 February 2022.
- ↑ "'Sex for grades': Undercover in West African universities" (in en). BBC News. 7 October 2019. https://www.bbc.com/news/av/world-africa-49907376/sex-for-grades-undercover-in-west-african-universities.
- ↑ "That BBC's sting operation in UNILAG". 15 October 2019.
- ↑ "About Us". University of Lagos (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 28 February 2022.
- ↑ Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; no text was provided for refs named:0
- University of Lagos
- Educational institutions established in 1962
- 1962 establishments in Nigeria
- Public universities in Nigeria
- Business schools in Lagos
- Medical schools in Nigeria
- Yunifásítì ní Nàìjíríà
- Pages with reference errors
- Pages with citations using unsupported parameters
- Pages containing cite templates with deprecated parameters
- CS1 Èdè Gẹ̀ẹ́sì-language sources (en)