Yusuf Haroun
Ìrísí
Dr. Yusuf Haroun | |
---|---|
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | Franklin University (Healthcare Administration), Lagos State University College of Medicine (LASUCOM) - MBBS (Bachelor of Medicine and Surgery |
Iṣẹ́ | Medical Doctor • Psychologist • Public Health Specialist |
Title | Founder of Love for Health Organization (LHO) |
Haroun Yusuf jẹ́ oníṣègùn òyìnbó àti onímọ̀ èrò-ọkà (psychologist) ọmọ orílẹ̀-èdè Nigeria. Òun ni olùdásílẹ̀ àjọ Love for Health Organisation (LHO), àjọ tí ó ń ṣe ìgbẹ́lárugẹ ìpolongo ètò-ìlera láwùjọ.[1]
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Edema, Grace (2023-09-28). "Leadership empowerment aids creativity, says medical expert". Punch Newspapers. Retrieved 2024-02-18.