Jump to content

Yvonne Ekwere

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Yvonne Ekwere
Ọjọ́ìbíYvonne Imoh-Abasi Glory Ekwere
3 Oṣù Kẹta 1987 (1987-03-03) (ọmọ ọdún 37)
Lagos State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaLagos State University
Iṣẹ́
Ìgbà iṣẹ́2008 – present

Yvonne Imoh-Abasi Glory Ekwere (bíi ni ọjọ́ kẹta oṣù kẹta ọdún 1987) tí orúkọ inagi rẹ jẹ Yvone Vixen Ekwere je agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ati òṣèré, òun sì ni atọkun ètò Ẹ-Weekly lórí Silver bird Television.[1] Ó ti ṣe atọkun ètò lórí Rythm 93.7 Fm náà.[2][3]

Ìbẹ̀rẹ̀pẹ̀pẹ̀ ayé àti ètò-ẹ̀kọ́ rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Vixen jẹ́ ọmọ ìpínlẹ̀ Akwa Ibom ni orile-ede Nàìjíríà, òun sì ní àbíkẹ́yìn nínú àwọn ọmọ méje, ìlú Èkó sì ni wọn bí sì. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Air force Primary School àti Holy Child College ni ìlú Èkó. Ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga Lagos State University, ní ibi tí ó ti kà ìwé imọ History and International Studies.[4]

O bẹ́ẹ̀ rẹ sì ni ṣe agbóhùnsáfẹ́fẹ́ ni ọdún 2008 ni ìgbà tí wọn fi ṣe atọkun fún eto Dance part lòri Rhythm 93.7 Fm.[5] Wọn gbà gẹ́gẹ́ bíi olóòtu fún eto E-Weekly lóri Silver bird Television. Ó ti ṣe Ifọrọwanilẹnuwo fún àwọn gbajúmọ ẹ̀yán bíi Olórí orile-ede Nàìjíríà tẹ́lẹ̀, Goodluck Jonathan, ó sì ti ṣe atọkun fún eto bíi Most Beautiful Girl in Nigeria 2012. Ní oṣù kẹwàá ọdún 2015, ó dá ètò tiẹ̀ sílẹ̀, ètò na ń jẹ Drive Time with Vixen.[6]

Yvonne tí kó pa nínú àwọn eré bíi 7 Inch Curve, Render to Caesar, Put a Ring on It àti Gidi Up .[7]

Year Award ceremony Prize Result
2009 Future Awards TV Personality of the Year Wọ́n pèé
2010 Wọ́n pèé
FAB Awards Wọ́n pèé
2011 Gbàá
Future Awards Wọ́n pèé
ELOY Awards 2011 Gbàá
The Nigerian Events Awards Best Event Coverage Gbàá
2012 City People Fashion Awards 2012 Most Stylish TV Presenter of the Year Gbàá
2013 2013 Nigeria Entertainment Awards TV Personality of the Year Wọ́n pèé

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]