Zainab Momoh
Ìrísí
Zainab Momoh (tí a bí ní ọjọ́ kẹta, oṣú kọkànlá, ọdún 1996) jẹ́ ọmọ orílè-èdè Naijiria tó ń gbá bọ́ọ̀lù badminton.[1]
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ó kópa nínú ìdíje ti ilè Africa ní ọdún 2017 àti 2018, ó sì wà lára àwọn tó gbégbá orókè.[2][3]
Àwọn àṣeyọrí rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ìdije ti ilẹ̀ Africa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àdàpọ̀
Year | Venue | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2018 | Salle OMS Harcha Hacéne,
Algiers, Algeria |
Peace Orji | Doha Hany | 11–21, 11–21 | Bronze |
2017 | John Barrable Hall,
Benoni, South Africa |
Dorcas Ajoke Adesokan | Doha Hany | 4–21, 26–24, 18–21 | Bronze |
Ìdíje àwọn ọ̀ọ́ ti ilè Africa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àdàpọ̀
Year | Venue | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2014 | Otse Police College,
Gaborone, Botswana |
Kingsley Nelson | Georges Paul | 13–21, 14–21 | Bronze |
Ìdíje gbogboogbò ti BWF
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àdàpọ̀
Year | Tournament | Partner | Opponent | Score | Result |
---|---|---|---|---|---|
2017 | Lagos International | Ramatu Yakubu | Thilini Hendahewa | 8–21, 5–21 | Runner-up |
2017 | Côte d'Ivoire International | Peace Orji | Simran Singhi | 11–21, 14–21 | Runner-up |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Players: Zainab Momoh". bwfbadminton.com. Badminton World Federation. Retrieved 14 October 2016.
- ↑ "Paul and Adesokan; Africa's Best Juniors". bcabadminton.org. Badminton Confederation of Africa. Retrieved 14 October 2016.
- ↑ "Host Win Women's and Mixed Doubles". bcabadminton.org. Badminton Confederation of Africa. Retrieved 14 October 2016.