Jump to content

Zakaria Dauda Nyampa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Zakaria Dauda Nyampa
Member of the
House of Representatives of Nigeria
from Adamawa
Lọ́wọ́lọ́wọ́
Ó gun orí àga
June 2023
ConstituencyMichika/Madagali
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí12 February 1973
AráàlúNigeria
OccupationPolitician

Zakaria Dauda Nyampa jẹ́ olóṣèlú orilẹ-ede Nàìjíríà . Lọwọlọwọ o ṣiṣẹ bi ọmọ ẹgbẹ kan ti o nsoju agbegbe Michika/Madagali ni ile ìgbìmò aṣòfin àgbà [1]

Igbesi aye ibẹrẹ

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bi Zakaria Dauda Nyampa ni ọjọ Kejìlá osù kejì ọdun 1973 o si wa láti ipinle Adamawa .

Ni ọdun 2019, Nyampa dije fun awọn idibo Ile-igbimọ Apejọ o si jawe olubori gẹgẹbi ọmọ ẹgbẹ kan ti o nsoju agbegbe Michika/Madagali Nibi idibo odun 2023, o tun dije lábé ẹgbẹ́ òṣèlú Peoples Democratic Party (PDP) o si jawe olubori, eleyii ti o fi se igba kejì gẹ́gẹ́ bi asofin. [2]

Zakaria Dauda Nyampa jẹ Musulumi.