Jump to content

Zayyad Ibrahim

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Zayyad Ibrahim
Member of the House of Representatives of Nigeria from Kaduna State
In office
2019–2023
Arọ́pòMohammed Hussaini Jallo
ConstituencyIgabi
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí22 March 1965
Ẹgbẹ́ olóṣèlúAll Progressives Congress
OccupationPolitician

Zayyad Ibrahim (ojoibi 1965) je olóṣèlú ọmọ Nàìjíríà. Ó sìn gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́ tó ń ṣojú ẹkùn ìpínlẹ̀ Ìgabi Federal Constituency ti ìpínlẹ̀ Kaduna nínú ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin 9th láti ọdún 2019 sí 2023. [1] [2]

Zayyad Ibrahim ni àbí ni ọjọ kejìlelógún oṣù kẹta ọdun 1965 láti ìlú Kaduna State.[3]

Ìrìnàjò òṣèlú

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ni inú ètò idibo atundi ọdún 2023 Ibrahim tún dije labẹ ẹgbẹ òṣèlú All Progressive Congress tí òsì fi idiremi sì ọwọ alátakò rẹ tinse Hussaini Muhammad Jallo tí ẹgbẹ òṣèlú Peoples Democratic Party.[4][5]