Jump to content

Zumbi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Bust of Zumbi in Brasília. The plaque reads: "Zumbi dos Palmares, the black leader of all races."

Zumbi (pipe: 'zoombee') (1645 – November 20, 1695), bakanna bi Zumbi dos Palmares, je olori to gbeyin larin awon Quilombo dos Palmares, ni ipinle Alagoas, Brazil.