Àtòjọ àwọn Ààrẹ ilẹ̀ Rùwándà
Ìrísí
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Rùwándà President of the Republic of Rwanda | |
---|---|
Flag of the President | |
Residence | Village Urugwiro, Kacyiru, Kigali |
Iye ìgbà | 7 years |
Ẹni àkọ́kọ́ | Dominique Mbonyumutwa |
Formation | 28 January 1961 |
Owó osù | 85,000 USD annually[1] |
Àyọkà yìí jẹ́ ìkan nínú àwọn àyọkà nípa ìṣèlú àti ìjọba ilẹ̀ Rùwándà |
---|
Government
|
Judiciary
|
|
United Nations in Rwanda
|
Àyọkà yìí ṣe àtòjọ orúkọ àwọn Ààrẹ ilẹ̀ Rùwándà láti ìgbà tí wọ́n dá ipò náà sílẹ̀ ní ọdún 1961 (nígbà Ìjídìde àwọn ará Rùwándà), títí di òní. Gẹ́gẹ́ bí òfin-ìbágbépọ̀ ṣe lànà rẹ̀, iṣẹ́ Ààrẹ ni gẹ́gẹ́bí olórí orílẹ̀-èdè ilẹ̀ Rwanda, ó sì ní agbára aláṣe tó pọ̀.[2] Wọ́n dìbò yan sí ipò ààrẹ yìí fún ọdún méje,[3] Ààrẹ yíò si yan Alákóso Àgbà àti gbogbo àwọn ará Kábínẹ́ẹ̀tì rẹ̀.[4]
Àwọn mẹ́rin ló ti jẹ Ààrẹ ilẹ̀ Rùwándà (láì ka àwọn Adípò Ààrẹ). Ààrẹ lọ́wọ́lọ́wọ́ ni Paul Kagame, láti 24 March 2000.
Key
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Political parties
- Party of the Hutu Emancipation Movement (Parmehutu)
- Rwandan Patriotic Front (RPF)
- Other factions
- Status
- Acting President
List of officeholders
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]No. | Portrait | Name (Birth–Death) |
Elected | Term of office | Ethnic group | Political party | Prime Minister(s) | ||
---|---|---|---|---|---|---|---|---|---|
Took office | Left office | Time in office | |||||||
Republic of Rwanda (part of Ruanda-Urundi) | |||||||||
– | Dominique Mbonyumutwa (1921–1986) |
— | 28 January 1961 | 26 October 1961 | 271 days | Hutu | Parmehutu | Kayibanda | |
1 | Grégoire Kayibanda (1924–1976) |
1961 | 26 October 1961 | 1 July 1962 | 248 days | Hutu | Parmehutu | Himself | |
Republic of Rwanda (independent country) | |||||||||
(1) | Grégoire Kayibanda (1924–1976) |
1965 1969 |
1 July 1962 | 5 July 1973 (deposed.) |
11 years, 4 days | Hutu | Parmehutu | Position abolished | |
2 | Juvénal Habyarimana (1937–1994)[lower-alpha 1] |
1978 1983 1988 |
5 July 1973 | 6 April 1994 (assassinated.) |
20 years, 275 days | Hutu | Military / MRND |
Nsanzimana Nsengiyaremye Uwilingiyimana | |
– | Théodore Sindikubwabo (1928–1998) |
— | 8 April 1994 | 19 July 1994 (ousted.)[lower-alpha 2] |
102 days | Hutu | MRND | Kambanda | |
3 | Pasteur Bizimungu (1950–) |
— | 19 July 1994 | 23 March 2000 (resigned.) |
5 years, 248 days | Hutu | RPF | Twagiramungu Rwigema Makuza | |
4 | Paul Kagame (1957–) |
2000 2003 2010 2017 |
24 March 2000 | 22 April 2000 | 24 years, 253 days | Tutsi | RPF | Makuza Habumuremyi Murekezi Ngirente | |
22 April 2000 | Incumbent |
Latest election
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Candidate | Party | Votes | % | |
---|---|---|---|---|
Paul Kagame | Rwandan Patriotic Front | 6,675,472 | 98.79 | |
bgcolor="Àdàkọ:Independent (politician)/meta/color"| | Philippe Mpayimana | Independent | 49,031 | 0.73 |
Frank Habineza | Democratic Green Party of Rwanda | 32,701 | 0.48 | |
Invalid/blank votes | 12,310 | – | ||
Total | 6,769,514 | 100 | ||
Registered voters/turnout | 6,897,076 | 98.15 | ||
Source: NEC Rwanda |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Top 15 Highest Paid African Presidents 2017". 15 December 2016. Archived from the original on 22 September 2019. Retrieved 27 May 2020.
- ↑ CJCR 2003, article 117.
- ↑ CJCR 2003, articles 100–101.
- ↑ CJCR 2003, article 116.
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/>
tag was found