Jump to content

Ìjọba ìbílẹ̀ Ọdẹ́dá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ọdẹ́dá
LGA and town
Motto(s): 
Ọdẹ́dá Gbayì
Ọdẹ́dá is located in Nigeria
Ọdẹ́dá
Ọdẹ́dá
Location in Nàìjíríà
Coordinates: 7°13′N 3°31′E / 7.217°N 3.517°E / 7.217; 3.517Coordinates: 7°13′N 3°31′E / 7.217°N 3.517°E / 7.217; 3.517
Country Nàìjíríà
StateÌpínlẹ̀ Ògùn
Government
 • Local Government Chairman and the Head of the Local Government CouncilSẹ̀míù Bọ́lá [1]
Area
 • Total1,560 km2 (600 sq mi)
Population
 (2006 census)
 • Total109,449
Time zoneUTC+1 (WAT)
3-digit postal code prefix
110
ISO 3166 codeNG.OG.OD

Ọdẹ́dá jẹ́ Ìjọba Ìbílẹ̀ àti ìletò kan ní Ìpínlẹ̀ Ògùn, ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Olú ilé-iṣẹ́ Ìjọba ìbílẹ̀ yí wà ní A5 highway7°13′00″N 3°31′00″E / 7.21667°N 3.51667°E / 7.21667; 3.51667. Ìjọba ìbílẹ̀ yí ní ibùsọ tí ó 1,560 km² tí àwọn olùgbé ibẹ̀ sì tó 109,449 gẹ́gẹ́ bí étò ìkànìyàn ti ọdún 2006 ṣe fi lọ́ọ́lẹ̀. Ìjọba ìbílẹ̀ yí súnmọ́ Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ pẹ́kípẹ́kí, tí ó sì pààlà pẹ̀lú Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ní ìlú Alọ̀gì.

Nọ́mbà ìfiránṣẹ́ (postal code) ìjọba ìbílẹ̀ yí 110.[2]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2019-08-09. Retrieved 2020-06-09. 
  2. "Post Offices- with map of LGA". NIPOST. Archived from the original on October 7, 2009. Retrieved 2009-10-20. .