Ẹlẹ́sìn Krístì
Ìrísí
Ẹlẹ́sìn Kírísítì tàbí Ọmọ lẹ́yìn Kírísítì tàbí ẹ̀sìn ìgbàgbọ́ ni eni tó nígbàgbọ́ nínú Ẹ̀sìn Kírísítì èyí tó jẹ́ ẹ̀sìn Abrahamu tó gbà pé Ọlọ́run kan ṣoṣo ló wà tó ń darí ayé àti ẹ̀kọ́ Jésù ọmọ Násárétì tí wọ́n gbà bí Messiah tó jẹ́ sísọ tẹ́lẹ̀ nínú Májẹ̀mú Láéláé, àti Ọmọ Ọlọ́run.[1][2]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ define.asp?key=13408&dict=CALD&topic=followers-of-religious-groups "Definition of Christian" Check
|url=
value (help). Cambridge Advanced Learner's Dictionary. Cambridge University Press. Retrieved 2010-18-01. Check date values in:|access-date=
(help) - ↑ "BBC — Religion & Ethics — Christianity at a glance", BBC