Yakubu Gowon
Ìrísí
Yakubu Gowon | |
---|---|
Olori Orile-ede Naijiria 3k | |
In office 1 August 1966 – 29 July 1975 | |
Vice President | J.E.A Wey gegebi Chief of Staff, Supreme Headquarters |
Asíwájú | Johnson Aguiyi-Ironsi |
Arọ́pò | Murtala Mohammed |
Oga Omose Agbogun | |
In office January 1966 – July 1966 | |
Asíwájú | Johnson Aguiyi-Ironsi |
Arọ́pò | Joseph Akahan |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | 19 Oṣù Kẹ̀wá 1934 Kanke, Plateau State, Naijiria |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Victoria Gowon |
Alma mater | Royal Military Academy Sandhurst University of Warwick |
Military service | |
Allegiance | Nigeria |
Branch/service | Adigun Nàìjíríà |
Years of service | 1954–1975 |
Rank | Ogagun |
[1][2]Yakubu tí àpèjẹ́ rẹ̀ ń jẹ́ Jack Dan-Yumma Gowon ni wọ́n bí ní kọkàndínlógún oṣù Kẹwàá, ọdún 1934 (19-10-1934) jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti apá Àríwá. Gowon jẹ́ Ọ̀gágun ní Ilé-iṣẹ́ Ológun ilẹ̀ Nàìjíríà, bẹ́ẹ̀ ni ó sì tún jẹ̀ olórí orílẹ̀-èdè Nàìjíríà láti ódún 1966 dé 1971. Kásìkò ìjọba rẹ̀ náà ni ilẹ̀ Nàìjíríà ja ogun abẹ́lé láti 1966 sí 1971, lábẹ́ ogágun Odumegwu Ojukwu tí ó fẹ́ gba òmìnira lọ́wọ́ ilẹ̀ Nàìjíríà.[3] [4]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn ìtọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Video: Watch Gen Gowon’s reaction as he was told he had been overthrown". P.M. News. 2019-04-25. Retrieved 2019-10-15.
- ↑ "Keyamo Replies Obasanjo: Yakubu Gowon Is The Boss Of All Bosses". Sahara Reporters. 2019-03-06. Archived from the original on 2019-10-15. Retrieved 2019-10-15.
- ↑ "Yakubu Gowon - head of state of Nigeria". Encyclopedia Britannica. 1934-10-19. Retrieved 2019-10-15.
- ↑ "THROWBACK: How Yakubu Gowon reacted to removal from office 43 years ago". Premium Times Nigeria. 2019-04-28. Retrieved 2019-10-15.