Femi Falana: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò
Ìrísí
Content deleted Content added
Created by translating the page "Femi Falana" |
(Kò ní yàtọ̀)
|
Àtúnyẹ̀wò ní 22:49, 23 Oṣù Ẹ̀bìbì 2018
Femi Falana | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | 30 December 1958 Lagos State, Nigeria |
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Iṣẹ́ | Lawyer |
Àwọn ọmọ | 1 |
Femi Falana SAN (Senior Advocate of Nigeria) Je agbejoro ati ajafeto omoniyan omo orile ede Naijiria ti won bi ni ojo Keedogbon Osu Kejila, odun 1958.(30/12/1958[citation needed]).[1] O dije dupo Gomina niipinle Ekiti ni odun 2007 sugbon o padanu ipo naa labe egbe oselu NCP (National Conscience Party) ti o ti figba kan je Alaga egbe naa jake-jado Naijiria ni odun 2011..[2]
Bakan naa, oun ni baba okorin, aderin posonu ati osere ori itage ti oruko re n je Falz.[3] Femi je oko fun arabinrin Funmi Falana ti oun naa tun je ajafeto omoniyan ni orile ede Naijiria.[4]
Awon itoka si
- ↑ "Femi Falana". informationng.com. Retrieved December 1, 2015.
- ↑ "Femi Falana". nigerianbiography.com. Retrieved December 1, 2015.
- ↑ "My wife didn't like our son's music career –Femi Falana". The Punch. Archived from the original on August 24, 2015. Retrieved December 1, 2015.
- ↑ Simeon Ndaji (5 August 2012). "Femi Falana left me at the mercy of judges – Funmi,wife". Vanguard News. http://www.vanguardngr.com/2012/08/femi-falana-left-me-at-the-mercy-of-judges-funmiwife/. Retrieved 21 June 2016.