Jump to content

Dayò Amúsà: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Content deleted Content added
Ìlà 1: Ìlà 1:
''' Dayọ̀ Amúsà''' ni wọ́n bí ní ìpínlẹ̀ [[Èkó]] tí ó jẹ ọmọ obìnrun àkọ́kọ́ nínú àwọn márùún nínú ẹbi rẹ̀. Bàbà rẹ̀ jé ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ [[Ògùn]] nìgbà tí ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ [[Èkó]]. Ó lọ sì ilé-ẹ̀kọ́ Mayflower ní ìlú [[Ìkẹ́nẹ́]] tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ Food Science and Technology ní ilé-ẹ̀kọ́ gbogbonìṣe [[Moshood Abíọ́lá Polytechnic]] ṣáájú kí ó tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹẹ́ eré ìtàgé rẹ̀ ní ọdún 2002. Ọpọ̀ ẹeré rẹ̀ tí ó ti kópa jùlọ ní eré orí ìtàgé èdè [[Yorùbá]]. Òun ni olùdásìlẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ PayDab tí ó pé méjì nílù [[Ìbàdàn]] àti [[Èkó]]. https://www.vanguardngr.com/2018/10/what-good-sex-means-to-a-woman-dayo-amusa/
''' Dayọ̀ Amúsà''' ni wọ́n bí ní ìpínlẹ̀ [[Èkó]] tí ó jẹ ọmọ obìnrun àkọ́kọ́ nínú àwọn márùún nínú ẹbi rẹ̀. Bàbà rẹ̀ jé ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ [[Ògùn]] nìgbà tí ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ [[Èkó]]. Ó lọ sì ilé-ẹ̀kọ́ Mayflower ní ìlú [[Ìkẹ́nẹ́]] tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ Food Science and Technology ní ilé-ẹ̀kọ́ gbogbonìṣe [[Moshood Abíọ́lá Polytechnic]] ṣáájú kí ó tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹẹ́ eré ìtàgé rẹ̀ ní ọdún 2002. Ọpọ̀ ẹeré rẹ̀ tí ó ti kópa jùlọ ní eré orí ìtàgé èdè [[Yorùbá]]. Òun ni olùdásìlẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ PayDab tí ó pé méjì nílù [[Ìbàdàn]] àti [[Èkó]].

=== Àwọn Àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀ ===
=== Àwọn Àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀ ===
Nollywood Female Face Of The Year 2017 Pink Awards
Nollywood Female Face Of The Year 2017 Pink Awards
Ìlà 10: Ìlà 9:
Merit Awards 2013 J15 Schiool Of Art
Merit Awards 2013 J15 Schiool Of Art
Achievers Award Of Honour J-KRUE 2013
Achievers Award Of Honour J-KRUE 2013
Award Of Excellence 2016 AFamily.<ref name="Informationcradle 2017">{{cite web | title=Dayo Amusa Biography, Age, Family, Married, Twin Sister, Songs and Movies | website=Informationcradle | date=2017-07-13 | url=https://informationcradle.com/africa/dayo-amusa/ | access-date=2019-03-14}}</ref>
Award Of Excellence 2016 AFamily.

=== Àwọn eré rẹ̀ tó ti kópa ===
=== Àwọn eré rẹ̀ tó ti kópa ===
AJÈGBODÒ 2006
AJÈGBODÒ 2006

Àtúnyẹ̀wò ní 14:21, 14 Oṣù Ẹ̀rẹ̀nà 2019

Dayọ̀ Amúsà ni wọ́n bí ní ìpínlẹ̀ Èkó tí ó jẹ ọmọ obìnrun àkọ́kọ́ nínú àwọn márùún nínú ẹbi rẹ̀. Bàbà rẹ̀ jé ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Ògùn nìgbà tí ìyá rẹ̀ jẹ́ ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Èkó. Ó lọ sì ilé-ẹ̀kọ́ Mayflower ní ìlú Ìkẹ́nẹ́ tí ó sì kẹ́kọ̀ọ́ Food Science and Technology ní ilé-ẹ̀kọ́ gbogbonìṣe Moshood Abíọ́lá Polytechnic ṣáájú kí ó tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹẹ́ eré ìtàgé rẹ̀ ní ọdún 2002. Ọpọ̀ ẹeré rẹ̀ tí ó ti kópa jùlọ ní eré orí ìtàgé èdè Yorùbá. Òun ni olùdásìlẹ̀ ilé-ẹ̀kọ́ PayDab tí ó pé méjì nílù Ìbàdàn àti Èkó.

Àwọn Àmì-ẹ̀yẹ rẹ̀

Nollywood Female Face Of The Year 2017 Pink Awards Best Actress Indigenous Nollywood Movies Awards 2014 Best Kiss In A Movie BON Awards 2013 Best Crossover Act YMAA 2014 Outstanding Performance 2010 The Ambassador Club Outstanding Achievers Awards 2011 Diamond Special Recorgnition Awards 2014 Merit Awards 2013 J15 Schiool Of Art Achievers Award Of Honour J-KRUE 2013 Award Of Excellence 2016 AFamily.[1]

Àwọn eré rẹ̀ tó ti kópa

AJÈGBODÒ 2006 OJÚ OWÓ 2007 ẸKAN ṢOṢO2008

ÒÓGÙN MI 2009

DÉWÙNMÍ ÌBẸ̀RẸÙ 2010 INÚ IDAA 2012

ARỌ́BA 2012
UNFORGIVABLE 2015
PATHETIC 2017
OMONIYUN.

Àwọn ìtọ́ka sí

  1. "Dayo Amusa Biography, Age, Family, Married, Twin Sister, Songs and Movies". Informationcradle. 2017-07-13. Retrieved 2019-03-14.