Bolanle Ninalowo: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò
Macdanpets (ọ̀rọ̀ | àfikún) Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit |
Macdanpets (ọ̀rọ̀ | àfikún) No edit summary Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit |
||
Ìlà 17: | Ìlà 17: | ||
'''{{PAGENAME}}''' tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ní ó (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ keje oṣù karùn-ún ọdún 1980) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò àti onímọ̀ Ìsirò-owó ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ṣùgbọ́n tí ó ń gbé ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Bí ó ṣe ń ṣeré tíátà, bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ akọrin. <ref name="Newtelegraph 2017">{{cite web | title=Why my marriage failed –Bolanle Ninalowo | website=Newtelegraph | date=2017-12-31 | url=https://www.newtelegraphng.com/2017/12/marriage-failed-bolanle-ninalowo-2/ | access-date=2019-12-17}}</ref><ref name="Nigeria 2018">{{cite web | last=Nigeria | first=Information | title=My success story in Nollywood – Bolanle Ninalowo | website=Information Nigeria | date=2018-03-21 | url=https://www.informationng.com/2018/03/my-success-story-in-nollywood-bolanle-ninalowo.html | access-date=2019-12-17}}</ref><ref name="Bada 2015">{{cite web | last=Bada | first=Gbenga | title=Rukky Sanda’s cousin becomes Nollywood’s new toast | website=Pulse Nigeria | date=2015-05-13 | url=https://www.pulse.ng/entertainment/movies/bolanle-ninalowo-rukky-sandas-cousin-becomes-nollywoods-new-toast/zq2s92h | access-date=2019-12-17}}</ref> |

==Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀== |
|||
A bí Nínálowó sí ìlú Ìkòròdú ni ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Kí óó dèrò ìlú-ọba ó kàwé àkóbẹ̀rẹ̀ àti sẹ̀kọ̀ndìrì rẹ̀ ní ìlú Èkó.<ref name="Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria 1980">{{cite web | title=Bolanle Ninalowo biography, net worth, age, family, contact & picture | website=Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria | date=1980-05-07 | url=https://www.manpower.com.ng/people/16035/bolanle-ninalowo | access-date=2019-12-17}}</ref> |
|||
==I gbìyànjú nídìí ìṣe sinimá àgbéléwò== |
|||
Gẹ́gẹ́ bí a ṣe sọ síwájú, Nínálowó jẹ́ onímọ̀ Ìsirò-owó, nítorí ìdí èyí, ó kọ́kọ́ ṣíṣe ni ilé-ìfowópamọ́ gẹ́gẹ́ bí Aṣèṣirò-owó (Accountant) fún ìgbà díẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà kí ó tó dára pọ̀ mọ́ ìṣe eré sinimá àgbéléwò ṣíṣe lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Bákan náà, nígbà tí ó padà sí Nàìjíríà, ó tún bá ilé-ìfowópamọ́ Guaranty Trust Bank ṣíṣe kí ó tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà. Nínálowó kò fi bẹ́ẹ̀ rọ́wọ́ mú nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò gẹ́gẹ́ bí olóòtú, ṣùgbọ́n lọ́dún 2014, ní ó ṣẹ̀ṣẹ̀ wá di gbajúmọ̀ nídìí ìṣe sinimá àgbéléwò.<ref name="360dopes 2018">{{cite web | title=Bolanle Ninalowo Biography & Net Worth | website=360dopes | date=2018-07-20 | url=https://www.360dopes.com/bolanle-ninalowo-biography-net-worth/ | access-date=2019-12-17}}</ref> <ref name="The Nation Newspaper 2017">{{cite web | title=BOLANLE NINALOWO: WHY I SEPARATED FROM THE MOTHER OF MY KIDS - The Nation Newspaper | website=The Nation Newspaper | date=2017-11-03 | url=https://thenationonlineng.net/bolanle-ninalowo-separated-mother-kids/ | language=la | access-date=2019-12-17}}</ref> |
|||
==Àwọn àmìn ẹ̀yẹ tí ó ti gbà àti àwọn tí wọ́n dárúkọ díje rẹ̀ fún== |
==Àwọn àmìn ẹ̀yẹ tí ó ti gbà àti àwọn tí wọ́n dárúkọ díje rẹ̀ fún== |
Àtúnyẹ̀wò ní 06:51, 17 Oṣù Ọ̀pẹ̀ 2019
Bolanle Ninalowo | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | May 7 1980 Nigeria |
Iléẹ̀kọ́ gíga | DeVry University |
Iṣẹ́ | Actor |
Ìgbà iṣẹ́ | 2010–present |
Bolanle Ninalowo tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Ní ó (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ keje oṣù karùn-ún ọdún 1980) jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò àti onímọ̀ Ìsirò-owó ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ṣùgbọ́n tí ó ń gbé ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà. Bí ó ṣe ń ṣeré tíátà, bẹ́ẹ̀ náà ló jẹ́ akọrin. [1][2][3]
Ìgbà èwe àti aáyan ìkẹ́kọ̀ọ́ rẹ̀
A bí Nínálowó sí ìlú Ìkòròdú ni ìpínlẹ̀ Èkó lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Kí óó dèrò ìlú-ọba ó kàwé àkóbẹ̀rẹ̀ àti sẹ̀kọ̀ndìrì rẹ̀ ní ìlú Èkó.[4]
I gbìyànjú nídìí ìṣe sinimá àgbéléwò
Gẹ́gẹ́ bí a ṣe sọ síwájú, Nínálowó jẹ́ onímọ̀ Ìsirò-owó, nítorí ìdí èyí, ó kọ́kọ́ ṣíṣe ni ilé-ìfowópamọ́ gẹ́gẹ́ bí Aṣèṣirò-owó (Accountant) fún ìgbà díẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà kí ó tó dára pọ̀ mọ́ ìṣe eré sinimá àgbéléwò ṣíṣe lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Bákan náà, nígbà tí ó padà sí Nàìjíríà, ó tún bá ilé-ìfowópamọ́ Guaranty Trust Bank ṣíṣe kí ó tó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ tíátà. Nínálowó kò fi bẹ́ẹ̀ rọ́wọ́ mú nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ sinimá àgbéléwò gẹ́gẹ́ bí olóòtú, ṣùgbọ́n lọ́dún 2014, ní ó ṣẹ̀ṣẹ̀ wá di gbajúmọ̀ nídìí ìṣe sinimá àgbéléwò.[5] [6]
Àwọn àmìn ẹ̀yẹ tí ó ti gbà àti àwọn tí wọ́n dárúkọ díje rẹ̀ fún
- Revelation of the Year, Best of Nollywood Award, 2010
- Best Supporting Actor of the Year ‘English’, City People Movie Award, 2017[7]
- The Best Actor in a Leading Role ‘English‘ Picture Perfect’ Best of Nollywood Awards (BON), 2017
- Best Actor of the Year ‘English’ City People Movie Award, 2018
- Best Actor of the Year ‘English’, City People Movie Award, 2018
Àtòjọ díẹ̀ nínú àwọn sinimá-àgbéléwò tí ó ti kópa
- Husbands of Lagos
- Ratnik
- Picture Perfect (2016 film)
- Road To Yesterday
- Tiwa’s Baggage
- Coming From Insanity
- Night Bus To Lagos
- Atlas
- A fire In The Rain
- 30 Years A Virgin
Àwọn Ìtọ́kasí
{{Reflist}
- ↑ "Why my marriage failed –Bolanle Ninalowo". Newtelegraph. 2017-12-31. Retrieved 2019-12-17.
- ↑ Nigeria, Information (2018-03-21). "My success story in Nollywood – Bolanle Ninalowo". Information Nigeria. Retrieved 2019-12-17.
- ↑ Bada, Gbenga (2015-05-13). "Rukky Sanda’s cousin becomes Nollywood’s new toast". Pulse Nigeria. Retrieved 2019-12-17.
- ↑ "Bolanle Ninalowo biography, net worth, age, family, contact & picture". Nigeria Business Directory - Find Companies, People & Places in Nigeria. 1980-05-07. Retrieved 2019-12-17.
- ↑ "Bolanle Ninalowo Biography & Net Worth". 360dopes. 2018-07-20. Retrieved 2019-12-17.
- ↑ "BOLANLE NINALOWO: WHY I SEPARATED FROM THE MOTHER OF MY KIDS - The Nation Newspaper". The Nation Newspaper (in Èdè Latini). 2017-11-03. Retrieved 2019-12-17.
- ↑ Emmanuel, Daniji (2017-10-18). "Full List Of Winners At The 2017 City People Movie Awards". City People Magazine (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2019-11-23.