Chidinma àti Chidiebere Aneke: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò
Macdanpets (ọ̀rọ̀ | àfikún) New Page Àwọn àlẹ̀mọ́: Àtúnṣe ojú fóónù Àtúnṣe ojú fóónù Advanced mobile edit |
(Kò ní yàtọ̀)
|
Àtúnyẹ̀wò ní 05:23, 19 Oṣù Bélú 2020
Chidinma àti Chidiebere Aneke | |
---|---|
Ọjọ́ìbí | Chidinma àti Chidiebere Aneke 24 Oṣù Kẹjọ 1986 Enugu, Ìpínlẹ̀ Enugu, Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | Òṣèrébìnrin àti Olóòtú sinimá àgbéléwò |
Chidinma àti Chidiebere Aneke jẹ́ gbajúmọ̀ ìlúmọ̀ọ́ká Òṣèrébìnrin àti Olóòtú sinimá àgbéléwò ìbejì tí wọ́n jọ ara wọn lọ́pọ̀lọpọ̀ nínú ẹgbẹ́ Nollywood tí wọ́n máa ń pè ní Ìbejì Aneke. Wọ́n jẹ́ àbígbẹ̀yìn àwọn òbí wọn àti ọmọ bíbí ìlú Ìpínlẹ̀ Enugu lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. [1]
Ìgbésí ayé àti ìkẹ́kọ̀ọ́ wọn láti ìbẹ̀rẹ̀
Wọ́n bí Chidinmma àti Chidiebere lọ́jọ́ kẹfà oṣù kẹjọ ọdún 6 1986 ní Ìpínlẹ̀ Enugu, lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ọmọ ilé-olórogún òníyàwó mẹta niwọ́n. Bàbá wọn jẹ olówó àti ọlọ́rọ̀ tí ó fi owó àti ọlà kẹ́ wọn láti ìgbà èwe wọn, ṣùgbọ́n èyí yí padà ní kété tí bàbá wọn ṣaláìsí, tí àwọn ẹbí sìn pín ogún rẹ̀ láàárín ara wọn.
Wọ́n bẹ̀rẹ̀ ìkẹ́kọ̀ọ́ wọn ní Ìpínlẹ̀ Enugu kí wọ́n tó tẹ̀ síwájú ẹ̀kọ́ gíga ní University of Nigeria, Nsuka níbi tí wọ́n ti kàwé gboyè nínú ìmọ̀ eto ìbánisọ̀rọ̀ àti ìmọ̀ ìfowópamọ́ àti ìsúná-owó lọ́tọ̀ọ̀tọ̀.[2]
Career
The Aneke twins joined the Nollywood industry in 1999 and acted in the movie ‘Ebuka’ which happens to be their first movie. The movie ‘Ebuka’ gave them an edge in Nollywood. In 2004, the Aneke twins rose to fame with the movie ‘Desperate Twins’ which earned them the nomination for The Most Promising Acts to Watch at the African Magic Viewers’ Choice Award. They have acted in over 80 movies. They have produced many Nollywood movies such as; ‘Heart of Isiaku’, ‘Onochie’, ‘Broken Ambition’’, and ‘Adaora’.
- ↑ "Nollywood’s Aneke Twins Bubbling @ 32 - THISDAYLIVE" (in en-US). THISDAYLIVE. 2018-08-11. https://www.thisdaylive.com/index.php/2018/08/11/nollywoods-aneke-twins-bubbling-32/.
- ↑ "Actresses Aneke Twins Full Biography - TIN Magazine" (in en-GB). TIN Magazine. 2017-04-22. https://www.takemetonaija.com/2017/04/actresses-aneke-twins-full-biography.html.
- ↑ "Biography & Net Worth of Nollywood Identical Actress Chidinma & Chidiebere Aneke - Austine Media" (in en-US). Austine Media. 2017-05-30. https://austinemedia.com/biography-net-worth-nollywood-identical-actress-chidinma-chidiebere-aneke/.