Jump to content

Àbàwọn (Stigma) (Fiimu ọdún 2013)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Stigma
Fáìlì:Stigma (2013 film) theatrical release poster.jpeg
AdaríDiminas Dagogo
Olùgbékalẹ̀Rivers State Ministry of Health
13Fatman Int'l Limited
Àwọn òṣèré
OlóòtúSiem Nkula and Eileen De Klerk
Ilé-iṣẹ́ fíìmù13Fatman Films
Déètì àgbéjáde
  • 1 Oṣù Kejìlá 2013 (2013-12-01)
Àkókò96 minutes
Orílẹ̀-èdèNigeria

Abawọn (Stigma) jẹ́ eré oníṣe lati orilẹ-èdè Nàìjíríà tí a gbé jáde ni ọdun 2013. Ere oniṣe yii da lori ìdẹ́yẹ sí ti àwọn eniyan ti arun kogboogun, EEDI n ba fínra n doju kọ. Abúlé kan ni Ipinle Rivers ni ète eré yii da le. Diminas Dagogo ni oludari eré naa nigbati awọn gbajugbaja osere bii Jackie Appiah, Hilda Dokubo àti Emeka Ike kopa ninu ere naa. Ile-iṣẹ elétò Ilera ti Ìpínlẹ̀ Rivers ni o se agbejade ere naa.

Ète/Àgbékalẹ̀ Eré

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]