Àbẹ̀ní (fíìmù)
Ìrísí
Abeni | |
---|---|
Fáìlì:Movie poster of Abeni.jpg | |
Adarí | Tunde Kelani |
Òǹkọ̀wé | Yinka Ogun François Okioh |
Àwọn òṣèré | Jide Kosoko Kareem Adepoju Abdel Amzat Bukky Wright |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Dove Media, Laha Productions Mainframe Film and Television Production |
Olùpín | Mainframe Film and Television Productions |
Déètì àgbéjáde |
|
Àkókò | 98 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria Benin |
Èdè | Yoruba French |
Abeni jẹ́ eré ìfẹ́ Nigerian-Beninese onípa méjì tí ọdun 2006 tí Tunde Kelani ṣe àkoso rẹ̀.[1][2] Ó ṣe àfihàn ìpinyà ti ó wà ní àwùjọ èyí tí ó jẹ́ abayọrisi ìgba ìkónilẹru, bótilẹ̀jẹ́pe Benin àti Nigeria fẹ̀gbẹ́kẹ̀gbẹ́.[3]
Ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Abeni jẹ́ ojúlówó ìtan òṣère Abeni tí ó jẹ́ ọmọ olówó. Ó pàdé Akanni tí òún wá láti ìdílé bọ̀ńkẹ́jẹ́. who hails from a more modest background. Wọ́n ti ṣe ìdána láti ṣègbéyàwó pẹ̀lu ẹlòmíràn lọ́tọ̀ọ̀tọ̀, ṣùgbọ́n ìpàde wọ́n yí ètò padà.
Àwọn Akópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Kareem Adepoju gẹ́gẹ́ bíi Baba Wande
- Abdel Hakim Amzat gẹ́gẹ́ bíi Akanni
- Sola Asedeko gẹ́gẹ́ bíi Abeni
- Amzat Abdel Hakim gẹ́gẹ́ bíi Akanni
- Jide Kosoko gẹ́gẹ́ bíi Abeni's father
- Bukky Wright
- ↑ Akande, Victor (2007-04-28). "Movie Review: Abeni". The Nation (Nigeria). Archived from the original on 2014-10-31. Retrieved 31 October 2014. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ Iyiola, Amos Damilare (2021-01-17). "Code-Switching, Code-Mixing and Code-Conflicting in Abeni by Tunde Kelani" (in en). KIU Journal of Humanities 5 (4): 169–174. ISSN 2522-2821. https://www.ijhumas.com/ojs/index.php/kiuhums/article/view/1112.
- ↑ Ogunleye, Foluke (2014-03-17) (in en). African Film: Looking Back and Looking Forward. Cambridge Scholars Publishing. ISBN 978-1-4438-5749-9. https://books.google.com/books?id=2msxBwAAQBAJ&dq=Abeni+2006+Tunde+kelani&pg=PA171.