Jump to content

Sola Asedeko

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Sola Asedeko
Ọjọ́ìbíIpinle Eko, Naijiria
Orílẹ̀-èdèNaijiria
Ọmọ orílẹ̀-èdèNaijiria
Iṣẹ́
  • osere
  • oludari
Ìgbà iṣẹ́2006 - lowolowo
Gbajúmọ̀ fúnAbeni
The Narrow Path

Ṣọlá Asedeko jẹ́ òṣèré fiimu tí Ìlu Nàìjíríà, àti olùdarí. Ó gbajúmọ̀ gẹ́gẹ́ bi Àbẹ̀ní fún ipa asíwáju rẹ̀ nínu Àbẹ̀ní, fiimu Nàìjíríà kan ti ọdún 2006, tí Túndé Kèlání ṣe ìtọ́sọ́nà rẹ̀.[1][2]

Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bí Asedeko ní Ìpínlẹ̀ Èkó, orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó ka ìwé mẹ́wa rẹ̀ ní Somori Comprehensive High School ní Ogba ṣááju kí ó tó lọ sí University of Lagos níbití ó ti gba oyè ẹ̀kọ́ nínu eré orí ìtàgé, lẹ́hìn náà ló tún gba oyè gíga nínu ìmọ̀ ìṣàkóso ìjọba.[3]

Iṣẹ́-ìṣe rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ eré ṣíṣe ní ọdún 2006, ọdún yìí kan náà ni ó kó ipa asíwájú nínu Àbẹ̀ní, fiimu kan tí Túndé Kèlání ṣe àgbékalẹ̀ àti ìdarí rẹ̀.[4][5] Fiimu náà mú kí ó di gbajúmọ̀ tó sì tún rí pípè láti kó ipa nínu fiimu Túndé Kèlání míràn tó padà gba àmì-èyẹ tí àkọ́lé rẹ̀ jẹ́ The Narrow Path, níbi tí ó tún ti kó ipa asíwájú gẹ́gẹ́ bi ọmọbìrin àbúlé kan tó ní láti yàn láàrin àwọn méjì tó féràn rẹ̀. Ó ti ṣe àfihàn nínu ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn fiimu Nàìjíríà.[6][7]

Àṣàyàn àwọn eré rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "THE SECRET AGONY OF ACTRESS SOLA ASEDEKO". nigeriafilms.com. Archived from the original on 18 April 2015. Retrieved 5 April 2015. 
  2. "THE SECRET AGONY OF ACTRESS SOLA ASEDEKO". TheNigerianVoice. Retrieved 5 April 2015. 
  3. Adeboyejo Ayo. "I am single, but not searching–Nollywood actress, Sola Asedeko". Newswatch Times. Archived from the original on 20 January 2015. Retrieved 5 April 2015. 
  4. "Movie Reviews" (in en-US). The New York Times. 2017-12-21. ISSN 0362-4331. https://www.nytimes.com/reviews/movies. 
  5. "Actress Sola Asedeko and her secret bodyguards". Modern Ghana. Retrieved 5 April 2015. 
  6. "Nollywood Actress Sola Asedeko Delivers Baby Boy". mjemagazine.com. Archived from the original on 10 April 2015. Retrieved 5 April 2015. 
  7. "Abeni". The Nation (Nigeria). Archived from the original on 31 October 2014. Retrieved 31 October 2014.