The Narrow Path
Ìrísí
The Narrow Path | |
---|---|
[[File:Fáìlì:Movie poster for The Narrow Path.jpg|200px|alt=]] | |
Adarí | Túndé Kèlání |
Òǹkọ̀wé | Túndé Kèlání Niji Akanni |
Àwọn òṣèré | Sola Asedeko Ayo Badmus Khabirat Kafidipe |
Orin | Beautiful Nubia Seun Owoaje |
Ìyàwòrán sinimá | Lukaan Abdulrahman Tunde Kelani |
Olóòtú | Mumin Wale Kelani Frank Efe Patrick |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Mainframe Film and Television Productions |
Olùpín | Mainframe Film and Television Productions |
Déètì àgbéjáde | 2006 |
Àkókò | 95 minutes |
Orílẹ̀-èdè | Nigeria |
Èdè | English and Yoruba |
The Narrow Path Ni eré oníṣẹ́ tí wọ́n gbé jáde ní ọdún 2006, tí alàgbà Túndé Kèlání gbé jáde tí ó sì darí rẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[1] Wọ́n ṣe àfàyọ eré yí láti inú ìwé onítàn The Virgin, ìwé tí Bayo Adebowale ke jáde.[2][3][4]
Agbékalẹ̀ eré náà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Eré yí ni ó sọ nípa ìṣòro tí ẹ̀dá ìtàn kan tí ó jẹ́ Awẹ̀ró tí ó ní láti mú ọ̀kan nínú àwọn ọkùnrin méjì Ọdẹ́jìmí ati Lápàdé tí ó jẹ́ ọmọ ọdẹ tí wọ́n ń dẹnu ifẹ́ kọ. [5][6][7]
Àwọn Ẹ̀dá-ìtàn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Sola Asedeko as Awero
- Segun Adefila as Dauda
- Ayo Badmus as Lapade
- Seyi Fasuyi as Odejimi
- Khabirat Kafidipe
- Joke Muyiwa
- Olu Okekanye
- Eniola Olaniyan
Àwọn itọ́ka sí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Ekenyerengozi, Michael Chima (2013). NOLLYWOOD MIRROR®. ISBN 9781304729538. https://books.google.com/books?id=RL01BgAAQBAJ&q=The+Narrow+Path-Tunde+Kelani+film&pg=PA21.
- ↑ "Continual Re-enchantment: Tunde Kelani's Village Films and the Spectres of Early African Cinema". framescinemajournal.com. Archived from the original on 2020-11-01. Retrieved 2021-05-20.
- ↑ "Narrow Path by Tunde Kelani". naijarules.com. Archived from the original on 2015-04-09. Retrieved 2021-05-20.
- ↑ Kerr, David; Banham, Martin; Gibbs, James; Plastow, Jane; Osofisan, Femi (2011). Media and Performance. ISBN 9781847010384. https://books.google.com/books?id=dFzMC-nHqi4C&q=The+Narrow+Path-Tunde+Kelani+film&pg=PA38.
- ↑ "Ẹda pamosi". Archived from the original on 2015-06-29. Retrieved 2021-05-20.
- ↑ "The Narrow Path". African Film Festival Inc.
- ↑ http://allafrica.com/stories/200802110080.html